Emi mimo Ekaabo Ah, emi mimo Eku ikale Emi alaayo Emi orun ooo Adaba mimo Eeeku ikale Agbara to ju'aiye ati orun lo Ekaabo Ekaabo Eku ikale Ekaabo o Eku ikale Ekaabo o Oh, eku ikale Odeee lati wa so okun di ogo Odeee lati wa so ekun di erin Odeee lati was so ibanuje dayo Eku ikale o Ekaabo Eku ikale o Ekaabo oo Baba eku ikale Ekaabo Emi mimo ti n so agbara di otun Ogo kan to gbe aiye ati orun Olowo ori awa oo Ekun to koja gbogbo oke pata Ode lati wa so ekun derin Ode lati wa so egan di ogo O ti de sarin wa oo Eku ikale Oti de sarin wa oo Ema ku ikale o Oti de sarin wa oo Ema ku ikale oo Eee emi mimo Eee emi mimo Adaba mimo odeee orun Eku ikale Ola san lo nile gbogbo eyan to n wo wa ebu ti yin Erin po nile gbogbo eyan to n wo wa ema ko ti yin Ekun tan, oshee gbe danu Ogo bori ogun agbara ota kpin Oti deee sarin wa o Akani eleru, o yo de bo si n de Emi mimo orun Eku ikale Emi alayo oo Eku ikale oo Emi olore Eku ikale Emi to n tan imole sipa okunkun ona Ema ku ikale oo Emi to shi ni ni iye lati mo oun to to ati oun to kan Eku ikale Emi to n so agbara di otun Eku ikale Emi to n so alaisan di alara pipe Eku ikale oo Emi to n so iku di iye Emi to n so iku di ayoo Oya emi to n shi ile omo Ekaaabo oo Emi to n shile omo fomo si meji, meta, merin Emi to n so iku di aiye oo Emi to n ji gbogbo oun to ti ku dide pata Ekaaboo sarin wa Ema ku ikale oo Ekaaaabo sarin wa Ema ku ikale Eku ikale oo