Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia - Imoremi şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia

albüm: Tales From A Small Room

Iye mà í p'èdè mo gbọ', iye mà í s'ọ'rọ' mo tẹ'tí

Ó wí, "Ọmọ mi o tí mo bí, mo fi s'ílẹ' fún yín
Ọmọ kan o ti mo bi, ka gbe ru'bo k'aye le toro
Omo mi o tí mo fẹ', Olúorogbo d'òrìṣà ká'yé
O mí p'èdè mo gbọ', iye mà í s'ọ'rọ' mo tẹ'tí

"Ọmọ mi o tí mo bí, mo fi s'ílẹ' fún yín

Ìyá mọ' mọ' rọ' wá o, rọ' wá o
Abiyamọ rọ' wá o, rọ' wá o
Imọ'remí ro wa o, rọ' wá o

Araye e gbo, O mí p'èdè mo gbọ', iye mà í s'ọ'rọ' mo tẹ'tí
Olúorogbo d'àgbà o d'ogbó
Iye mà í s'ọ'rọ' mo tẹ'tí
Olúorogbo d'òrìṣà ká'yé
Ìyá mọ' mọ' rọ' wá o, rọ' wá o
Abiyamọ rọ' wá o, rọ' wá o
Imọ'remí ro wa o, rọ' wá o
Abiyamọ rọ' wá o, rọ' wá o
Imọ'remí ro wa o, rọ' wá o
Abiyamọ rọ' wá o, rọ' wá o
Ìyá mọ' mọ' rọ' wá o, rọ' wá o
Abiyamọ rọ' wá o, rọ' wá o
Imọ'remí ro wa o, rọ' wá o

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar