Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia - Iwure şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia

albüm: Lord of Letters


Sebi gbogbo eda lo nf'alafia
Gbogbo eda lo nfe'losiwaju
Ani gbogbo eda lo nfe'dunnu o
Ise owo won ni o je
Sebi gbogbo eda lo nfe'dera o
Gbogbo eda lo nfe ilera
Ani gbogbo eda lo nfe'tunu o
Ise owo won ni o je

Sebi gbogbo eda lo nf'alafia
Gbogbo eda lo nfe'losiwaju
Ani gbogbo eda lo nfe'dunnu o
Ise owo won ni o je
Sebi gbogbo eda lo nfe'dera o
Gbogbo eda lo nfe ilera
Ani gbogbo eda lo nfe'tunu o
Ise owo won ni o je
Ojo gbogbo lo dara f'onisuru
Igba gbogbo lo l'ayo fun asooto
Oun gbogbo lo derun f'afenifere
Osi o ni ba o n'ile yi o
Ofo o ni se o, ma wi pe, "Ase o!"
Ase o!
Ase o!

Ojo gbogbo lo dara f'onisuru
Igba gbogbo lo l'ayo fun asooto
Oun gbogbo lo derun f'afenifere
Osi o ni ba o n'ile yi o
Ofo o ni se o, ma wi pe
"Ase!"
Ase!
Ase!
B'a ti wi beeni yio ri
B'a ti wi beeni yio ri o

B'a ti wi beeni yio ri

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar