Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia - Omoniyun şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia

albüm: Lord of Letters


Owo mi osi, owo mi otun
Owo mi mejeji ma fi gb'omo jo o
Owo mi osi, owo mi otun
Owo mi mejeji ma fi gb'omo jo o
Owo mi osi, owo mi otun
Owo mi mejeji ma fi gb'omo jo o
Omo ni gbe ni, omo ni pe ni l'oja aye
Omoniyun, omonide, omoniwura
Omo l'aworan ere o
Omo ni wo'le de ni, omo ni pe ni l'oja aye
Omoniyun, omonide, omoniwura
Omo l'aworan ere o
Owo mi osi, owo mi otun
Owo mi mejeji ma fi gb'omo jo o
Omo ni gbe ni, omo ni pe ni l'oja aye
Omoniyun, omonide, omoniwura
Omo l'aworan ere o
Omo ni wole de ni, omo ni pe ni l'oja aye
Omoniyun, omonide, omoniwura
Omo l'aworan ere o
Owo mi osi, owo mi otun
Owo mi mejeji ma fi gb'omo jo o
Owo mi osi, owo mi otun
Owo mi mejeji ma fi gb'omo jo o
Owo mi mejeji ma fi gb'omo jo o

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar