Bí 'gbà bà mí dùn Òun gbogbo a dá bí ere Gbogbo àyé a má yìn o Wọn a má pọn ẹ le l'ọtun, l'ósì o Bí 'gbà bà yi pere Gbogbo ilé a wá pa lọ-lọ Wọn a má kí ní l'atọọkàn, woah Ọwọ èpò, òun ní wón ń bá ní là o Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná) ♪ K'alẹ, kò lé dùn Là ṣé ń jí l'ówúrò s'ìṣẹ Ẹní àyé kàn kó lo jẹjẹ Kà má fí t'ẹní p'ọlá o Kò s'òun ta o rí-rí A tí r'ọmọ aládé tó ń d'ẹrú A dẹ tí r'ẹní tó ń ro pín, tó ń d'ọlọrọ Kà má f'aigbọ'n jìn s'ọ̀gbun (ọ̀gbun) Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná) ♪ Ilé wúrà ń d áhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná) Ilé wúrà a má dáhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná) Woah-oh, ilé wúrà a má dáhòrò (ilé wúrà) Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn) Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo Wọn a ní, "Mò rí o ná, mo ń bo" (mo rí o ná) Ilé wúrà Owó ò hùn kò ra tí 'gbẹ̀yìn (Mo rí o ná) mo rí o ná Ilé wúrà Owó ò hùn kò rà tí 'gbẹ̀yìn