Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia - Itana Odede şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia

albüm: Lord of Letters

Níbí wọn gbé ń ṣe'un tó yẹ kà ṣé láyé o
Níbí wọn gbé ń ṣe'un tó dára, ọrẹ, ọrẹ
Níbí wọn gbé ń ṣeré aládùn, 'ládùn, 'ládùn, 'ládùn
Níbí wọn gbé ń ṣ'ájọyọ tẹrín-tọyaya
ẸniỌbankẹ (ẸniỌbankẹ) ṣé b'áwọn lo l'érè òní
ẸniỌbankẹ (ìtàna ọdẹdẹ) ṣé b'áwọn lo ń ṣe'jo
ẸniỌbankẹ (ìtànṣán oòrùn) ṣéb'òun l'ọga òkùnkùn
ẸniỌbankẹ (atọnìsọna) ọrẹ, kà lọ, kà jọ débẹ o
Kà lọ, kà jọ débẹ o, woah-oh-oh

Ke s'ọmọdé pẹ'lú ọdọ, èwe àti májesìn
Ke s'obìnrin pel'ọkùnrin, àgbààgbà, àgbà ìlù
Ke s'ẹní tí ńbẹ l'okò, tó ń ṣíṣẹ kò le dá
Ke s'ẹní tó re, tí ò l'àgbàrá mọ
Wípé, ah, ẸniỌbankẹ (ẸniỌbankẹ) ṣé b'áwọn lo l'érè òní
ẸniỌbankẹ, (ìtàna ọdẹdẹ) ṣé b'áwọn lo ń ṣe'jo o
ẸniỌbankẹ (ìtànṣán oòrùn) ṣéb'òun l'ọga òkùnkùn
ẸniỌbankẹ (atọnìsọna) ọrẹ, kà lọ, kà jọ débẹ o

Má gbẹsẹ́ lọkánkán o, ní méjì-méjì
Áà tí b'orí ọfọ àti ìbànújẹ́, woah
Máà mì bo wùn o oh
Ààní boo fẹ d'oókòtò
Gbogbo ẹni là pé síbẹ', ehn, là pé síbẹ'
Gbogbo ẹni là pé síbẹ', po
L'agbo onidẹra, gbogbo wá là wá níbẹ' (bẹẹni)
Aató débẹ, gbogbo wá là wá níbẹ', po
ẸniỌbankẹ (ẸniỌbankẹ) ṣé b'áwọ lo l'érè òní
ẸniỌbankẹ (ìtàna ọdẹdẹ) ṣé b'áwọn lo ń ṣe'jo o
ẸniỌbankẹ (ìtànṣán oòrùn) ṣéb'òun l'ọga òkùnkùn
ẸniỌbankẹ (atọnìsọna) ọrẹ, kà lọ, kà jọ débẹ o
(ẸniỌbankẹ) ẸniỌbankẹ, ṣé b'áwọ lo l'érè òní
ẸniỌbankẹ (ìtàna ọdẹdẹ) ṣé b'áwọn lo ń ṣe'jo o
ẸniỌbankẹ (ìtànṣán oòrùn) ṣéb'òun l'ọga òkùnkùn
ẸniỌbankẹ (atọnìsọna) ọrẹ, kà lọ, kà jọ débẹ o
(ẸniỌbankẹ)
Kà lọ, kà jọ débẹ o
(Gbogbo wá là wá níbẹ', a wá níbẹ' o, a wá níbẹ', po)
(A wá níbẹ', gbogbo wá là wá níbẹ')

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar