Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia - Eefo Egbe şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia

albüm: Lord of Letters


Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá o, wa ka lọ
Kà má'yọ wálé, jẹ ká lọ o, ma fòyà
Ẹgbẹ onire lo mí pe wá o, wá ká lọ o
Kà má dùn wálé, jẹ ká lọ o, má bẹ̀rù

Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto
Abaniṣe, k'ọlá ko lé dùn
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto
Abaniṣé, k'ọlá kò lé to
Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá o, wa ka lọ
Kà má'yọ wálé, jẹ ká lọ o, ma fòyà
Ẹgbẹ onire lo mí pe wá o, wá ká lọ o
Kà má dùn wálé o, jẹ ká lọ o, má bẹ̀rù

Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o
Obìnrin ìlù, oninure o
Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọ'la
Àwọn ọmọ ọ'la, ọmọ ọgbọn
Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o
Ọkùnrin ìlú, oninure o
Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọlá
Àwọn ọmọ iyì, ọmọ ọgbọn
Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá o, wa ka lọ o
Kà má'yọ wálé, jẹ ká lọ o, ma fòyà
Ẹgbẹ onire lo mí pe wá o, wá ká lọ o
Kà má dùn wálé o, jẹ ká lọ, má bẹ̀rù
Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o
Obìnrin ìlù, oninure o
Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọ'la
Àwọn ọmọ ọ'la, ọmọ ọgbọn
Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o
Ọkùnrin ìlú, oninure o
Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọlá
Àwọn ọmọ iyì, ọmọ ọgbọn
Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá o, wa ka lọ o
Kà má'yọ wálé o, jẹ ká lọ o, ma fòyà
Ẹgbẹ onire lo mí pe wá o, wá ká lọ o
Kà má dùn wálé o, jẹ ká lọ o, má bẹ̀rù

Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto
Abaniṣe, k'ọlá ko lé dùn
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto
Abaniṣé, k'ọlá kò lé to
Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá, wa ka lọ o
Kà má'yọ wálé, jẹ ká lọ o, ma fòyà
Ẹgbẹ onire lo mí pe wá o, wá ká lọ o
Kà má dùn wálé o, jẹ ká lọ, má bẹ̀rù
Wa ka lọ
Jẹ ká lọ (kà má dùn wálé)
Wa ka lọ
Jẹ ká lọ (kà má dùn wálé)
Wà ká lọ
Jẹ ká lọ (kà má dùn wálé) wà ká lọ

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar