1.Ona ara l'Olorun wa, Ngba sise Re l'aiye; A nri 'pase Re l'or' okun, O ngun igbi l'esin. Ma beru mo, enyin mimo, Orun t'o su be ni, O kun fun anu: y'o rojo Ibukun s'ori nyin. Mase da Oluwa l'ejo, Sugbon gbeke re le; 'Gbat o ro pe o binu, Inu Re dun si o. Afoju ni alaigbagbo, Ko mo 'se Olorun; Olorun ni Olutumo, Y'o m'ona Re ye ni. Amin.