Awa Yin O, Olorun Awa njewo Re pe iwo ni oluwa Gbgbo aye fi ori ba le fun o Baba Aye titi lai Iwo ni eniti gbobo awon Angeli Nki gbe pe Orun ati gbogbo agbara Ti mbe ninu won Iwo ni eniti awon Kerubu ati awon Serafu Kigbe pe ni gba gbogbo pe. Mimo Mimo Mimo Oluwa Olorun awon omo ogun Orun oun aiye Kun fun ola nla ti o go Re Egbe awon Aposteli Ti o logo Yin o Ogba awon Woli Ti o dara, Yin o Ogun awon Matyr Ti o dara Yin o Ijo Mimo eniyan Olorun Ni gbogbo aye Nje wo o Re Baba en ola nla Ti Ko ni i pe kun Ati Omo Re nikansoso Olo la O lo 'to Emi Mi mo pelu Olutunu ni Kristi, iwo ni Oba Ogo Iwo ni Omo lailai ti Baba Nigbati iwo tewogba fun ara Re lati gba eniyan la O ko korira inu wundia Nigbati o segun oro iku tan O si ijoba orun sile fun gbobo Awon onigbagbo O jojo ni owo otun Olorun Ninu Ogo ti Baba Awa gbagbo pe O mbo wa Lati se Onidajo wa Nitorinaa ni awa se ngbadura Si odo Re Ran awon omo odo Re lowo Ti iwo ti fi eje Re Iyebiye ra pa da Se won ki a le ka won kun awon eniyan Mimo Re Ninu ogo Ti ko ni pe kun Oluwa gba awon eniyan Re la Ki iwo ki o si fi Ibukun fun awon eniyan i ni Re J' O ba won Ki o si ma gbe won leke lailai Awa ngbe o ga Ni o jo jumo Awon si nfi ori bale ni Oru ko Re Titi aye ti ko ni pe kun Fiyesini Oluwa Lati pa wa mo loni ni ailese Oluwa Sanu fun wa Sa a nu fun wa Oluwa, je ki anu Re ki o ma ba le wa Gegebi awa ti n gbeke wa le o Oluwa, Iwo ni mo Gbe ke le, Lai, ma je kin da mu