Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Ago Onile şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Sun No Dey Sleep


Àgò onílé, a mà dé, àwa ni (ẹyin wo nùu?)

Àgò onílé, a mà dé, àwa ni (ẹ káàbọ' o!)

Àgò onílé, a mà dé, àwa ni (a tí ń retí yín!)

Àgò onílé, a mà dé, àwa ni (ẹ má wo 'lẹ' o!)

Àgò onílé, a mà dé, àwa ní

A dé, mo seb'á'wa náà ni, ẸniỌ'bánkẹ' gangan, a tún dé
Ati tún dé o
A ma dé o, kò s'éwu l'ẹ'gbẹ'rún ẹ'kọ, ẹ máa bá wa kálọ, a tún dé
Láti ilé ọgbọn
A dé, seb'á'wa náà ni, ọmọ ọ'dọ' àgbàgbà, a tún dé
Ẹni bá ṣe 're
Ire ni ó ma rí, ẹni bá sì ṣè 'kà, àbámọ' ni ó jẹ l'óde, ayé
Ẹ f'ìwà ṣ'ọlá
Ẹ f'ọlá m'ẹbí, f'owó m'aráàdúgbò, ẹnìkan ò m'ẹ'hìn ọ'la, ẹ yé
Tẹẹ' jẹ'jẹ'
Yíyí l'ayé ń yí, ẹní kàn l'ọ'tẹ' yìí, ẹ' bá jẹ' a rọra ṣ'ayé
F'òtítọ' ṣ'ọ'rẹ'
K'áyé ó le r'ójú, ẹ jẹ' á tún 'lẹ' yìí ṣe, k'ára ó rọ gbogbo wa, ẹ yé!

Àgò onílé a mà dé àwa ni

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar