Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Teramo şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Sun No Dey Sleep


Arákùnrin, tẹ'ra mọ, tẹ'ra mọ
Tẹ'ra mọ 'ṣẹ', ìbẹ'rẹ' ìí ṣ'oníṣẹ'
Olólùfẹ', tẹ'jú mọ, tẹ'jú mọ
Tẹ'pá mọ' 'ṣẹ', ọ'la ń bọ' wá da
Arábìnrin, tẹ'ra mọ, tẹ'ra mọ
Tẹ'ra mọ 'ṣẹ', ìbẹ'rẹ' ìí ṣ'oníṣẹ'
Olólùfẹ' tẹ'jú mọ, tẹ'jú mọ
Tẹ'pá mọ' 'ṣẹ', ọ'la ń bọ' wá da

Àsìkò layé, bí ò bá ì yí kan ni
Á dà bí ẹni'pe ènìyàn ò mọ'ọ' ṣe rárá
Ṣùgbọn tí 'gbà bá tó, tí 'ràwọ' ẹ'dá ń tàn
Kò s'ẹ'ni tó le dí ni l'ọ'nà
Fì 'dẹ'ra fún wa, Ọba, fì 'bùkún fún wa
Wá fi'ṣẹ' yìn wá o, ká má d'èr'o ẹ'yìn l'áyé o
Fì 'dẹ'ra fún wa, Ọba, fì 'bùkún fún wa
K'ọ'jọ' ayé wa kó gùn, k'ólóyin
Fì 'dẹ'ra fún wa, Ọba, fì 'bùkún fún wa
Ká má ṣ'iṣẹ' àṣedànù, ká má d'èrò ẹ'yìn l'áyé o
Fì 'dẹ'ra fún wa, Ọba, fì 'bùkún fún wa
K'ọ'jọ' ayé wa kó dùn kan lẹ'
Ìgbà mà l'ọlá, yíyí níí yí kan ni
Ẹni ò ní sùúrù ní t'ojú bọ 'lé kiri
F'òwúrọ' ṣiṣẹ', ko f'òtítọ' si o
Ṣèbí sùúrù ló jù, ọba ìwà
Fì 'dẹ'ra fún wa, Ọba, fì 'bùkún fún wa
Wá fi'ṣẹ' yìn wá o, ká má d'èr'o ẹ'yìn l'áyé o
Fì 'dẹ'ra fún wa, Ọba, fì 'bùkún fún wa
K'ọ'jọ' ayé wa kó gùn, k'ólóyin
Fì 'dẹ'ra fún wa, Ọba, fì 'bùkún fún wa
Ká má ṣ'iṣẹ' àṣedànù, ká má d'èrò ẹ'yìn l'áyé o
Fì 'dẹ'ra fún wa, Ọba, fì 'bùkún fún wa
K'ọ'jọ' ayé wa kó dùn kan lẹ'

Arákùnrin, tẹ'ra mọ, tẹ'ra mọ
Tẹ'ra mọ 'ṣẹ', ìbẹ'rẹ' ìí ṣ'oníṣẹ'
Olólùfẹ,' tẹ'jú mọ, tẹ'jú mọ
Tẹ'pá mọ' 'ṣẹ', ọ'la nbọ' wá da
Arábìnrin, tẹ'ra mọ, tẹ'ra mọ
Tẹ'ra mọ 'ṣẹ', ìbẹ'rẹ' ìí ṣ'oníṣẹ'
Olólùfẹ', tẹ'jú mọ, tẹ'jú mọ
Tẹ'pá mọ' 'ṣẹ', ọ'la ń bọ' wá da

Arákùnrin, tẹ'ra mọ, tẹ'ra mọ
Tẹ'ra mọ 'ṣẹ', ìbẹ'rẹ' ìí ṣ'oníṣẹ'
Olólùfẹ', tẹ'jú mọ, tẹ'jú mọ
Tẹ'pá mọ' 'ṣẹ', ọ'la ń bọ' wá da
Arábìnrin, tẹ'ra mọ, tẹ'ra mọ
Tẹ'ra mọ 'ṣẹ', ìbẹ'rẹ' ìí ṣ'oníṣẹ'
Olólùfẹ', tẹ'jú mọ, tẹ'jú mọ
Tẹ'pá mọ' 'ṣẹ', ọ'la ń bọ' wá da
Arákùnrin, tẹ'ra mọ, tẹ'ra mọ
Tẹ'ra mọ 'ṣẹ', ìbẹ'rẹ' ìí ṣ'oníṣẹ'
Olólùfẹ', tẹ'jú mọ, tẹ'jú mọ
Tẹ'pá mọ' 'ṣẹ', ọ'la ń bọ' wá da

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar