Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Eniobanke Gangan şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Oriojori-Eternal Spirits


Eléré ọba dé, ẹ p'ọ'dọ', ẹ p'àgbà pé'ré yá o
Onílù ayọ' ré, ẹ pa'gbo àríyá, ijó yá o
Eléré ọba dé, ẹ p'ọ'dọ', ẹ p'àgbà pé'ré yá o
Onílù ayọ' ré, ẹ pa'gbo àríyá, ijó yá o
Anikú ò ní p'ọmọ rẹ, àrùn ò ní ṣe yín o
Ọjọ' òní l'ayọ' rẹ, bẹ'rẹ', tú'jú ká ọ'rẹ' o
Ani o bẹ'rẹ', máa jó (bẹ'rẹ' máa jó o)
Dìde máa jó, o ba de nàró maa jó o
Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan
F'ẹ'sọ' máa jó, o jàre, f'àyà m'aa jó o
Rè'dí o m'aa jó, oba de ra'sẹ' m'aa jó o
Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan

Adá'jọ', ọjọ' pé, ara rẹ ò gbà'bọ'dè, tú'ra ká o
Onílù ayọ' ré, ẹ pa'gbo àríyá, ijó yá o
Adá'jọ', ọjọ' pé, ara rẹ ò gb'odi, tú' ra ká o
Onílù ayọ' ré, ẹ pa'gbo àríyá, ijó yá o
Ani'kú ò ní p'ọkọ rẹ, àrùn ò ní ṣe yín o
Ọjọ' òní l'ayọ' rẹ, bẹ'rẹ', tú'jú ká ọ'rẹ' o
Ani o bẹ'rẹ' máa jó (bẹ'rẹ' máa jó o)
Dìde máa jó, o ba de nàró maa jó o
Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan
F'ẹ'sọ' máa jó o jàre, f'àyà m'aa jó o
Rè'dí o maa jó, ani o ra'sẹ' maa jó o
Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan

Ani'kú ò ní p'aya rẹ o, àrùn ò ní ṣe yín o
Ọjọ' òní l'ayọ' rẹ, bẹrẹ', tú'jú ka, òré o
Ani o bẹ'rẹ' máa jó (bẹ'rẹ' máa jó o)
Dìde o máa jó, a ni o nàró maa jó o
Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan
F'ẹ'sọ' máa jó o jàre, f'àyà m'aa jó o
Rè'dí o m'aa jó, mo ní o ra'sẹ' maa jó o
Onítèmi àtàtà, ẸniỌbánkẹ' gangan

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar