Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Osomaalo şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Keere


Bó sáré ma fò o, bó dẹ rìn, ma sáré
(Bó sáré ma fò o, bó dẹ rìn, ma sáré)
Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á ṣe bí ọbọ
Bó wọ'lé ma lòṣó o, ma dèrìgì pẹ̀lú eléyín
(Bó wọ'lé ma lòṣó o, ma dèrìgì pẹ̀lú eléyín)
Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á ṣe bí ọbọ
Wọlé o bá nmú ńkan mí (gbèsè rẹ ni o máa sán)

Gbèsè rẹ ni odẹ máa sán

(Gbèsè rẹ ní o máa sán)

Gbèsè rẹ ni òdẹ máa sán

Bó pọn'gi ma tèle, bo wè'kun, ma wọ'nú ibú
(Bó pọn'gi ma tèle, bo wè'kun, ma wọ'nú ibú)
Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á se bí ọbọ
Bó mú 'nú aginjù lọ, ma fi ìgboyà wọ'nú igbó
(Bó mú 'nú aginjù lọ, ma fi ìgboyà wọ'nú igbó)
Ọdẹ tí ó mú ìjímèrè, ìyẹn náà á ṣe bí ọbọ
Wọlé o bá ńmú ńkan mi (gbèsè rẹ ní o máa sán)

Gbèsè rẹ ni odẹ máa sán

(Gbèsè rẹ ní o máa sán)

Gbèsè rẹ ni odẹ máa sán

Gbèsè rẹ ni o máa sán!

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar