Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Ireti-Ogo şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Soundbender


Ẹni tó dúró kó dúró régé, aṣòtítọ' oní'nú re
Ọjọ' òní le korò díẹ', ó di dandan k'ọ'la wa ó dára
Jọ'wọ', jẹ ká mú'ra, ká má ṣe ṣiyèméjì
Ọjọ' ọ'la ń bọ', ó nbọ' wá dùn, ṣ'o gbọ'?
Ọ'rẹ' mi, m'ọ'kàn le, gb'ójú rẹ s'íbi gíga
Ìrètí ògo rẹ ń bọ' wá d'ire

Gbọn'ra jìgì, k'o dúró gbágbá
Má ì dá'wọ' dúró, ọ'rẹ' mi, ìbẹ'rẹ' la wà o
Taraṣàṣà, má ṣe m'ọ'wọ' l'ẹ'rán o
"Báòkú ìṣe ò tán o," l'àwọn àgbà nwí
Jọ'wọ', jẹ ká mú'ra, ká má ṣe ṣiyèméjì
Ọjọ' ọ'la ń bọ', ó ń bọ' wá dùn ṣ'o gbọ'?
Ọ'rẹ' mi,m'ọ'kàn le, gb'ójú rẹ s'íbi gíga
Ìrètí ògo rẹ ń bọ' wá d'ire

Gbọn'ra jìgì, k'o dúró gbágbá
Má ì dá'wọ' dúró, ọ'rẹ' mi, ìbẹ'rẹ' la wà o
Taraṣàṣà, má ṣe m'ọ'wọ' l'ẹ'rán o
"Báòkú ìṣe ò tán o," l'àwọn àgbà ń wí
Jọ'wọ', jẹ ká mú'ra, ká má ṣe ṣiyèméjì
Ọjọ' ọ'la ń bọ', ó ń bọ' wá dùn, ṣ'o gbọ'?
Ah, ọrẹ mi, m'ọ'kàn le, gb'ójú rẹ s'íbi gíga
Ìrètí ògo rẹ ń bọ' wá d'ire
Jọ'wọ', jẹ ká mú'ra, ká má ṣe ṣiyèméjì
Ọjọ' ọ'la ń bọ', ó ń bọ' wá dùn, ṣ'o gbọ'?
Ọ'rẹ' mi, m'ọ'kàn le, gb'ójú rẹ s'íbi gíga
Ìrètí ògo rẹ ń bọ' wá d'ire
Ìrètí ògo rẹ ń bọ' wá d'ire
Ìrètí ògo rẹ ń bọ' wá d'ire
Ìrètí ògo rẹ ń bọ' wá d'ire

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar