Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Orin Adetutu şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Táabákú


B'ogiri o la'nu popo, alangba o ni wo 'be
Seb'aya lo fi nfa, a woye a mi'ri f'aye
Iyalode alantakun, a ta'di m'eyin pepe
Wole o ki mi ore mi esinsin, sebi 'le aye la b'ogbon
Woah, oh, woa, oh, oh-oh, Adetutu, ma se gbo t'elegan iyawo
Jowo, wo mi, o tun mi fe

A-ri-teni-mo-wi, alomo-ni-lona-oja
Iyawo e ku inawo, sebi ile aiye la b'owu?
Mo se b'owo oba l'eyin nna, oko re ngbegun onihoho
Duro na o gbo tuntun iyawo, sebi ile aiye nla b'ote?
Woah, oh, woa, oh, oh-oh, Adetutu, ma se tele t'olopuro
Moni, wo mi, o tun mi fe

Ajé sọ'mọ nù bí òkò, l'óri kárà-kátà
Kìràkìtà yí ò mà d'ọlà o, ṣèbí 'lé ayé la b'ówó
Dàbọ' wá 'lé olólùfẹ', b'ó ti wù k'ó lè korò
Lai s'ole, lai rewesi iyawo, a o jo de ibi itunu
Woah, oh, woa, oh, oh-oh, Adetutu, mase gbo telegan iyawo,
Jowo, wo mi otun mi fe
Woah, oh, woa, oh, oh-oh, Adetutu, mase tele to l'opuro
Moni o, owo mi otun mi fe

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar