Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Akeegbe Nla şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Táabákú


Aìí dára k'á má kù sí 'bì kan
Òun l'ó d'ífá f'Ádìgún òkè
Ọ'rẹ' ọmọdé, olùfẹ' àlejò
Ẹmulẹwù ò mà b'ẹ'nìkan jà
Ẹ fún wọn ní'gbá kan o, ẹ fún wọn ní'gbá méjì
Ẹ fi t'àgbà sílẹ' níbẹ' o, akèègbè ńlá
K'ó máa yí
K'ó máa yí lọ
Aani k'ó máa yí o, mo ni k'ó máa yí lọ
Ẹwoo bo ti fun-fun lau, lau
Toro lọfún, dugbẹ ní kun
Ègbé t'ọba lọ, ẹ má gbàgbé ìjo ye o
Ẹ fún wọn ní'gbá kan o, ẹ fún wọn ní'gbá méjì
Ẹ fi t'ọmọdé yẹn silẹ o, akèègbè nlá
K'ó máa yí
Ani k'ó máa yí lọ
Mo ni k'ó máa yí o
Ani mo ni k'ó máa yí lọ
Boda Ẹmulẹwu, ẹ̀yìn ná ẹti ẹdẹ tirà ka
Kẹ kólé, kẹ rà moto, àbí tí ẹ te ra'ṣọ títún sọ rùn, aa'f'ẹmu yí ṣáà
Ah, ìyá wá, ẹ'jẹ' à fí iyin nun lẹ
Ṣé aṣọ ká ń bẹ tènìyàn wọ, tí e ṣá'ṣọ ní?
Dem go dey look, dem go dey point, dem go dey laugh
As if, no be cloth I wear
No be cloth I swear
You go dey talk, dey shout, dey beg
As if, no be cloth I wear
Sister, no be, no be cloth I wear
You wear your red, or your green, or your blue
My brother, no be cloth I wear
Sister, no be cloth I wear
Ẹ fún wọn ní'gbá kan o, ẹ fún wọn ní'gbá méjì
Ẹ fi t'àgbà sílẹ' níbẹ' o, akèègbè ń lá
K'ó máa yí
Ani k'ó máa yí lọ
Mo ni k'ó máa yí o
Ani mo ni k'ó máa yí lọ
Ẹwoo bo ti fun-fun lau, lau

No be cloth I wear
Ẹwoo bo ti fun-fun lau, lau

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar