Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Abanije şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Atunluto


Ọta inu, ọta ode
Kò gbèrò miran ju pe ko bajẹ
Gbogbo aye n gbimọ wipe ko le da
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ
Ọta 'nu, ọta ode
Kò gbèrò miran ju pe ko bajẹ o
Gbogbo aye n gbimọ wipe ko le da
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ
Abanijẹ n ṣ'eni ko mọ pé kó dá
Abanijẹ n ṣ'eni ko mọ pé kó dá
Ọta 'nu, ọta ode
Kò gbèrò miran ju pe ko daru
Gbogbo aye n ṣ'eto wipe ko le jọ o
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ
Ọta 'nu, ọta ode
Kò gbèrò miran ju pe ko daru
Gbogbo aye n ṣ'eto wipe ko le jọ
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ
Ọta 'nu, ọta ode
Kò gbèrò miran ju pe ko bajẹ
Gbogbo aye n gbimọ wipe ko le da
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ
Ọta 'nu, ọta ode
Kò gbèrò miran ju pe ko bajẹ
Gbogbo aye n gbimọ wipe ko le da
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ
Ọta 'nu, ọta ode
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ
Ọta 'nu, ọta ode
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ
Ọta 'nu, ọta ode
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ
Ọta 'nu, ọta ode
Abanijẹ ṣ'enu gọngọ lati sọrọ

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar