Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Beriwon şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Atunluto


Gbogbo àwọn tọ ní fẹ eto ilu
Gbogbo àwọn tọ n pero po le da
Gbogbo awon abaniṣe k'ọla k'ole dun
Gbogbo awon ọlọwọ atunṣe o
Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn)
Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ
Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ)
Asiko ti to
Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ
Ẹ jẹ a gbáradi
Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ)
Asiko ti to, oh-oh
Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán
Ẹgbẹ a tuni to

Gbogbo àwọn ìyá ọlọwọ itọju (ah-ah-ah-ah)
Gbogbo agba ọlọgbọn atọni s'ọna
Gbogbo awọn ti o fẹ ki're ko sọnu (ah-ah-ah-ah)
Gbogbo awọn ọdọ akíkanjú ẹni ire
Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn)
Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ
Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ)
Asiko ti to
Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ
Ẹ jẹ a gbáradi
Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ)
Asiko ti to, oh-oh
Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán
Ẹgbẹ a tuni to
Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn)
Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ
Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ)
Asiko ti to
Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ
Ẹ jẹ a gbáradi
Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ)
Asiko ti to, oh-oh
Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán
Ẹgbẹ a tuni to
Bẹẹ riwọn l'óna ọja, è ma bami ke si wan ye (bẹẹ riwọn)
Bẹẹ riwọn l'oke odo, ẹ bam' bawọn sọrọ
Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ)
Asiko ti to
Ọjọ taa wí yẹn o, o ti sunmọ
Ẹ jẹ a gbáradi
Pe 'ṣẹ ti ya ọ (iṣẹ ti ya ọ)
Asiko ti to, oh-oh
Ọjọ taa wí yẹn o, o ti dé tán
Ẹgbẹ a tuni to

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar