Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - Ese Odo şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Huruhara

Ohun meji l'o mo, oo mo t'eni t'o mo mejila
Ohun merin l'o mo, oo mo t'eni to mo merinla
O wa nke, "Wo-wo-wo", o mi ke "Wiriwiri-warawara"
O nro, "Pi-pi-pi", o mi dun, "Huruhara-harahuru"
O wa nke "Wo-wo-wo", o mi ke "Wiriwiri-warawara"
O nro, "Pi-pi-pi", o mi dun, "Huruhara"
Ki l'o nbe l'oko o t'akinkanju o ri ri?
Kini nbo l'aginju t'ode agba o i rin kan?
Ani o ba ke, "Wo-wo", ode a dake, "Pin-pin"
Bo ba bu rara, agba a mura ija sile
Bo ba yi'ra pada, ode a t'agbara se
Bo ba wa d'omi, ipade d'ese
O d'ese odo (odo)
Ipade d'ese odo (odo)
O d'ese odo (odo)
Ipade d'ese odo (odo)

Ohun meji l'o mo, oo mo t'eni t'o mo mejila
Ohun merin l'o mo, oo mo t'eni to mo merinla
O wa nke, "Wo-wo-wo", o mi ke "Wiriwiri-warawara"
O nro, "Pi-pi-pi", o mi dun, "Huruhara-harahuru"
O wa nke "Wo-wo-wo", o mi ke "Wiriwiri-warawara"
O nro, "Pi-pi-pi", o mi dun, "Huruhara"
Ki l'o nbe l'oko o t'akinkanju o ri ri?
Kini nbo l'aginju t'ode agba o irin kan?
Ani bo ba ke, "Wo-wo", ode a dake, "Pin-pin"
Bo ba bu rara, agba a mura ija sile
Bo ba yi'ra pada, ode a t'agbara se
Ha, bo ba wa d'omi, ipade d'ese
O d'ese odo (odo)
Ipade d'ese odo (odo)
O d'ese odo (odo)
Ipade d'ese odo (odo)

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar