Kishore Kumar Hits

Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band - A O Dide şarkı sözleri

Sanatçı: Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band

albüm: Huruhara


Alágbára ńwùga, kò ṣe 'fura
O l'òun l'ọ̀gá ìgbà
A f'ọwọ ọlá gbà ní tẹ'yókù mọ'lẹ'
Kò má ṣ'ení to-to f'ohùn
Alágbára ńko ní láyà jẹ
O lòun l'ọga àsìkò
Ìkà ẹlẹ́nu eewọ af'ọrọ f'àní l'étí ya
Kò má ṣ'ení to jẹ f'ohùn
Alakọri o mọ wípé a o dídé o
(Wípé) a o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé a o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, ta o dídé o
Àní kò mọ wípé a o dídé o
Ko mọ wípé a o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé a o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, ta o dídé o

Ẹgbá mẹ́rìnlá l'oúnjẹ òwúrò
Iko méjìlá ni t'ọ'sán o
Ẹnì to kàn lo mọ, kò ní ṣe'rú ẹ mọ
Ípàṣán ẹlẹrújẹjẹ
Ní'lé wọn tí kò ní l'ọrọ lo
L'odò, a o ríbí sọrọ
Àgbà ń d'orikodò, ń ronú o
Kò má sẹni to jẹ f'ohùn
Abanijẹ, o mọ wípé a o dídé o
Wípé a o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé a o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, ta o dídé o
Abanije, ko mọ wípé a o dídé o
Wípé a o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé a o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, tá o dídé o

K'oníkálukú gbéra ni'lẹ
Òní l'ọjọ' ìtúsílẹ̀
A fẹ ko're jáde, ìtura mà dé o
Ọnà lá, kà'yé wá tóóró
Ẹ jọ'wọ', ẹ sọ fún wọn wípé à o dídé o
Wípé a o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé a o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, tá o dídé o
Ani k'e sọ fún wọn wípé à o dídé o
Wípé à o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé a o dídé pọ láì ro tí'bí
Ọjọ' dé tàn, ta o dídé o
À o dídé
À o dídé pẹ'lú ìgboyà
À o dídé pọ
À o dídé o
Àní k'e sọ fún wọn o, à o dídé o
À o dídé pẹ'lú ìgboyà
À o dídé pọ ooo
À o dídé o
Àní, k'e sọ fún wọn o, à o dídé
À o dídé pẹ'lú ìgboyà
Wípé à o dídé pọ, woah-oh-oh
À o dídé o
Ẹjọ'wọ, ẹ sọ fún wọn o, a o dídé o
À o dídé pẹ'lú ìgboyà
À o dídé pọ, yeah, ey-ey
À o dídé o

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar