Kishore Kumar Hits

Tope Alabi - Tire Ni şarkı sözleri

Sanatçı: Tope Alabi

albüm: Agbelebu


Tire ni, Tire ni Tire ni Tire ni
Tire ni Oluwa
Mofisile fun o O
Tire ni Oluwa
Owuro, Osun mi Ale mi tire ni
Kini im ba je gba de re oo
Gbogbo aiye mi dowo re o baba mi o
Tire ni o, Tire ni o, Tire ni ooo
Gbo gbon ti mo ni... On ti mo ni tireni o
Gbo gbon ti mo ni tire ni o
Tire ni o Tire ni o. Iwo ni mo fi fun laye ati orun
Tire ni baba o
Oluwa tire ni o
Baba iwo lo ni maa gbogo loooo
Tire ni Tire ni Tire ni tire ni tire ni oluwa
Awon kan laye
Awon gbekele keke
Iwo ni
Tire ni o Tire ni o Tire ni ooo

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar