Eru Ogo re bami Eru ogo re bami o Eleni ogo Onite ogo Alade ogo Ololainu ogo Elewa ogo Kikidaogo ogo Akodaogo ogo Ogoninu ogo Asaju ogo Igbeyin ogo Eru ogo re bami o 1. Boti n gbe ninu ogo O n Sogo Lori ite o Ogo lo wo laso Oloju ogo ni Eda Orun fogo fun aramanda ogo to yii won ka Baba ologo julo to da ohun gbogbo pelu ogo. 2. Boti leruniyi to Ite idajo taanu togo Ogo otun iseju si iseju Ewa ti o lakawe Nigbogbo igba sigba Ododo logo re Awon orile -ede gbogbo nsola Lori ogo re 3. Olorun to ta sanmo pelu ogo Iwo lasaju ologo to leruniyi iba baba iba Call: alogoleru Response: toloke Call: eleruniyi Response: tonile Call: onile ola Response: alade ogo Call: ofi kikida ogo