Kishore Kumar Hits

Tope Alabi - Eyin Oluwa şarkı sözleri

Sanatçı: Tope Alabi

albüm: Alagbara


Eje ka fope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipaa re po o e
Be laanu re duro o lai-lai
(Eyin Oluwa), eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga o-o-o-o-o (egbe ga)
Eyin Oluwa o, halleluyah
O hun logaju o-o-o-o, halleluyah

Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti Kerubu, Serafu korin si o
Oun re ru awon omi okun
(Eyin Oluwa), eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo
(Eyin Oluwa o), eyin Oluwa o, halleluyah
O hun logaju ooo, halleluyah

Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori ododo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo (agbara re po pupo)
Eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah
Eyin Oluwa o, halleluyah
O hun logaju oooo, halleluyah

Iyanju ogo re ti ki pade
Iyan wo ina re to kun fun abo
Onu gbogbo to da, o da won dara-dara
Ni ohun te angeli juba ni gbagbo
Eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah
Eyin Oluwa o, halleluyah
O n logaju oooo, halleluyah

Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo
Eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah
Eyin Oluwa o, halleluyah
O un logaju oooo, halleluyah
Eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah
Eyin Oluwa o, halleluyah
O n logaju oooo, halleluyah

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar