Kishore Kumar Hits

Tope Alabi - Ebiire Ko şarkı sözleri

Sanatçı: Tope Alabi

albüm: From the Archive of Tope Alabi: Sound Track Compilation (Version 1)


Eh, eh, eh, ebiire ko
Ah, ah, ah, ebiire ko
Aimo kan pani ko fi
Iye rira laba se satani teri yen
Ona agbelebu lo le yoni
Eh, eh, eh, ebiire ko
Ah, ah, ah, ebiire ko
Aimo kan pani ko fi
Iye rira laba se satani teri yen
Ona agbelebu lo yonko
Uhm, uhm, uhm, ebiire ko oo, (ebiire ko)
Oh, oh, oh, ebiire ko (ebiire ko)
Ona kan wa todara loju e opin re iparun ma jasi o
Agbejoro agba lole gbani
Uhm, uhm, uhm ebiire ko ooo
Oh, oh, ebiire ko
Ona kan wa todara loju e opin re iparun ma jasi o
Agbejoro agba lole gbani

Uh, uh, uh, ebiire ko (ebiire ko)
La, la, la, ebiire ko
Ona toro yen, ko gbeniyan meji
Ona toto lati ba Jesu joba o
Alayileri lo le ye
Uh, uh, uh, ebiire ko
La, la, la, ebiire ko
Ona toro yen ko gbeniyan meji
Ona toto lati ba Jesu joba o
Alayileri lo le ye

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar