Kishore Kumar Hits

Tope Alabi - Mowowa Aye şarkı sözleri

Sanatçı: Tope Alabi

albüm: From the Archive of Tope Alabi: Sound Track Compilation (Version 1)


Ewo aiye o, ewo aiye o, bo won ti mi se ka, e wo aiye o
Ewo aiye o, eeeh
Ewo ara o, ewo ore o, boti mi se ra won, e wo ore o
Awon kan lon gba ra won, awon kan lo se ra won
B'araiye o ri yin olorun wo niyan
Ewo ore o boti mi se ra won
Ewo aiye o, ewo aiye o, bo won ti mi se ka, e wo aiye o
B'araiye ti ri ni yen o, ti ri ni yen o
Ewo ore o, ewo ore o, boti mi se ra won, e wo ore o
Awon kan lon gba ra won, awon kan lo se ra won
Bi araiye o ri yin olorun wo niyan
Ewo ore o boti mi se ra won
Oni kumo, oni kondo
Ore to finu ja ni logun gidi
Ika aiye po lo jara (on be ninu ore o)
Ori mi, eda mi, mama gbe mi ko won o
E wo aiye o boti mi se ra won
E wo aiye, e wo ile aiye o
Ewo aiye o, ewo aiye o, bo won ti mi se ka, e wo aiye o
E wo eniyan, e wo ore imule
Ewo ara o, ewo ore o, boti mi se ra won, e wo ore o
Awon kan lon gba ra won, awon kan lo se ra won
Bi araiye o ri yin olorun wo niyan, ewo ore o boti mi se ra won

Mo wo iwa aiye o, mo wo iwa eniyan
Mo wo iwa aiye o, mo wo iwa eniyan
Oro ile aiye wa kan bobo
Eni ta o lero lo fi iku pa eniyan
Aiye lee tebi, tore, e sora
(Mo wo iwa aiye o), mo wo iwa aiye o, mo wo iwa eniyan (mo tiri ki n to so)
Mo wo iwa aiye o, mo wo iwa eniyan
Oro ile aiye wa kan bobo
Eni ta o lero lo fi iku pa eniyan
Aiye lee tebi, tore, e sora
Awon to nu ni mu lo po la pa eniyan
Bo ti nu ni la tinu eje ni won ti un ro bi (abi, e ori?)
Kalara so ra o ko si enikan feni kan
Aiye le tegbon, taburo, e sora o
Aiye le
Mo wo iwa aiye o, mo wo iwa eniyan
Mo wo iwa aiye o, mo wo iwa eniyan
Oro ile aiye wa kan bobo
Eni ta o lero lo fi iku pa eniyan
Aiye lee tebi, tore, e sora

Oni kaluku un lo waiye ti e, (mo w'aiye temi)
Alaiye lo laiye e, ke so dada
Arugun omo kin mama bawon bi
Aiye le tomo, tiya, e sora
Mo wo iwa aiye o, mo wo iwa eniyan
Mo wo iwa aiye o, mo wo iwa eniyan
Oro ile aiye wa kan bobo
Eni ta o lero lo fi iku pa eniyan
Aiye lee tebi-tore, e sora
Mo wo iwa aiye o, mo wo iwa eniyan
Mo wo iwa aiye o, mo wo iwa eniyan
Oro ile aiye wa kan bobo
Eni ta o lero lo fi iku pa eniyan
Aiye lee tebi-tore e sora
O le pa o le anytime

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar