Asan laiye ati nkan gbogbo To nwu ni bii wura didan Kole gbeni nu etan aiye Owo ofo la o pada lo Ki o towo iwo orun Ki o tode Iwo osupa Emi a beleda mi laja ♪ Igba a lo bi agogo Odo wa n sise e ewu O nsun mowa eda ko kaakun Se giri ero o nbo dede Ki o towo iwo orun Ki o tode Iwo osupa Emi a beleda mi laja ♪ Bi sun re bada ohun lomi Baiye bata ni afa o mora Ife re ju tara atebi Isun re dara yo sun aigbe Ki o towo iwo orun Ki o tode iwo osupa Emi a beleda mi laja ♪ Tete ba eleda laja Korun towo kosupa tode Ko yi pada lona egbe Olugbala lo npe o wa Ki o towo iwo orun Ki o tode Iwo osupa Emi a beleda mi laja