Kishore Kumar Hits

Tope Alabi - E Yin Oluwa, Halleluyah şarkı sözleri

Sanatçı: Tope Alabi

albüm: Hymnal, Vol. 1


Eje ka fope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipaa re po o e
Be laanu re duro o lai-lai
Eyin o Oluwa o halleluyah
Egbe e ga o halleluyah
Eyin Oluwa o halleluyah
O hun logaju o halleluyah
Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti Kerubu Serafu korin si o
Oun re ru awon omi okun
Eeyin o Oluwa o halleluyah
Egbe e ga o halleluya
Eyin Oluwa o halleluyah
O hun logaju o halleluyah
Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori ododo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo
Eyin o Oluwa o halleluyah
Egbe e ga o halleluyah
Eyin Oluwa o halleluyah
O hun logaju o halleluyah
Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo
Eyin o Oluwa o halleluyah
Egbe e ga o halleluyah
Eyin Oluwa o halleluyah
O un logaju o halleluyah
Eyin o Oluwa o halleluyah
Egbe e ga o halleluyah
Eyin Oluwa o halleluyah
O un logaju o halleluyah

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar