Kishore Kumar Hits

Tope Alabi - L'oro L'ero Ati Ni'se şarkı sözleri

Sanatçı: Tope Alabi

albüm: Hymnal, Vol. 1

Emi o fe o oluwa, agbara ati apata
Iwo ni igbala mi, ilu olodi mi
Ile isho mi giga, ti owo ota ko le kan
Ofa mi jade wa lati inu omi nla
Titi le mi o fe lorolero ni ise
Loro lero ati ni ise, loro lero ati ni ise
Loro lero ati ni ise, Loro lero ati ni ise
Emi o fe o oluwa, iwo ni iranwo mi
Emi o gbeke e le igbala owo otun re
Iranwo re yo mumi duro shin shin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele lero ni ise
Loro lero ati ni ise, loro lero ati ni ise
Loro lero ati ni ise, Loro lero ati ni ise
Emi o ma yo si oluwa, oba ati ase mi
Fibukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade de mi, o ko mi lonare
Ola ati ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise
Loro lero ati ni ise, loro lero ati ni ise
Loro lero ati ni ise, Loro lero ati ni ise

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar