Ohun ti ẹda ma je laye, inu e lo wa Ibi ti ẹda ma de laye, inu e ẹ lo wa (oh oh oh) Ẹda o le mu ona oko kan,ko gbe lagodo dani Ero to lo sodo nikan ni yo pọn omi bo wa'le Toju inu e Toju inu e Toju inu e oh Toju ero re oh Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo, ke gbo o ke gba Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ ati ero re Tori ohun to ba n ro(toju inu rẹ) Ohun na ni yo je jade(toju inu rẹ) Ninu Irinajo aye rẹ (toju inu rẹ) Oh oh oh oh (ati ero re) Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo, ke gbo o ke gba Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ ati ero re Akaba ti ẹda ma gun l'aiye inu rẹ lero wa Ẹda ti o wo aso alárè inu e a dan Alai niran ti o n ki oba ninaro, ko le jọ yẹ laye laye Tori eni to ba mo iwura, la mi ta a fun Ero rere lo n gbe ni de bi giga (toju inu rẹ) Bẹẹni mo wí (toju inu rẹ) Ko ya toju inu rẹ (toju inu rẹ) To kan rẹ ba todi ko ya fo (ati ero re) Isesi e larin ero Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo, ke gbo o ke gba Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ, pẹlu ero re Toju inu rẹ (toju re) Toju inu rẹ (guide your heart with all diligence) Toju inu rẹ (bẹẹni mo wí se) Ati ero re (tori e ibẹ ni gbogbo ohun ti a fe je laye wa) Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo, ke gbo o ke gba Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ ati ero re (toju re daada, se dada) ♪ Awujo awon to n ba rin Awa o lati inu ẹ Eyan meji o le rin papo La Lai sepe won mo owo ara won Obun ti o fi omi osu kan kanra To wa pa la gan na ni were Oye ko mo pe ologiri omo ekun ni Eni to n gbọn Toju inu rẹ (to wa pade e ni ma lulu) Toju inu rẹ (abi é rí pe oro ti bu se) Toju inu rẹ (bẹẹni mo wí se) Ati ọkan rẹ (oje ya tọju inu rẹ) Ero gbogbo (tori oje ki lo fere) Ero gbogbo (awọn kon se ore arire ma bọ) Ero gbogbo Ero gbogbo, ke gbo o ke gba Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ, pẹlu ero re Ero ti ẹda ro laye lo n gbe won rin irin ajo otọ tó Bi ọkan eda ba buru laye, aiye rẹ a sha mala mala Agborin rin irin ẹwà bo lọnà, ijapa wa koto sọnà fún Se ere taja fi ogun odun sa ni fa n ga lesin fin Yan Koto ti ijapa wa sile naa ni o ni je ko lo Odun ti Kinihun ti pa era je se laja se ayan Ma sọ o ero okan re Be positive all the time bo ti wun ko ri Ero inú do ri ayanmọ kodo ke ya sọ Opo ohun ti ẹda ro, o bawon rin irin ajo Eni ro rere, o si ṣe é Eyan to ro ika o sí se Opo ohun ti a ri laye eda ero won ni Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ, pẹlu ero re Toju inu rẹ Toju inu rẹ Toju inu rẹ Toju ero re Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo, ke gbo o ke gba Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ, pẹlu ero re Toju inu rẹ Toju inu rẹ Toju inu rẹ Ati ero re Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo Ero gbogbo ke gbo o ke gba Toju inu rẹ, toju ọkan rẹ, pẹlu ero re Toju inu rẹ toju ọkan rẹ pẹlu ero re Toju inu rẹ toju ọkan rẹ pẹlu ero re