Kishore Kumar Hits

Tope Alabi - Do That Thing şarkı sözleri

Sanatçı: Tope Alabi

albüm: Igbowo Eda


Alabo to peye
Ohun lo n gbe me ro titi di iwo yi oo eeh
Oore ofe ti mo n je
Anu ye po lo mu mi yan fa lala
Babara l'ore to mu mi ji to mu mi sun
Mo gbo ope oore de
Aramada l'ore ti mo le gba pa
Ti mo le gbese mo la ju mo fi ri
Oto l'ore pe mo le je mo le mu
Won f'ounje nu mi oo
Anu l'ore pe ke mi jade kin wole
Alaafia ni
So when I put together
Oore to se laye mi
Yet none stop
Mo m'ope wa
So when I put together
Oore to se laye mi
Yet none stop
Mo m'ope wa
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
O seun
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
O seun
Oya mi le nu o jo mi loju
O ka mi laya mi o riru ri
Won wa n bere lowo mi
Ewo ni mo to la
Ewo ni mo je
Se t'oro o ye rara
Ni ma salaye
Baba lo n do that thing for me
Mo ma r'anu gba ni
Tani iba m'okolo mi tele
Anu gba aye mi wo ni
Mo m'oore
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
O seun
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
O seun
Wo n bere b'omi se de nu agbo
Iginle lo je ko s'eni to ye
Won fe mo bo re se po lara ope
Ko de le ye anybody
Asiri ninu eledumare ni
Baba lo n gbese owo gbara
Lemi se gbohun ope mi soke oo
Ohun lo n f'aye mi se glamour
Lemi se n mo ope igba gbogbo mi wa
(He's doing that thing)
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
O seun
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
Iwo lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupe lo jojo
O seun
Jesu ti gbe soke wa n be lowo re
Agbe o ga oo
Agbe o ga
Kristi ti gbe soke wa n be lowo re
Agbe o ga o Olorun ife
Iwo ti gbe soke wa n be lowo re
Agbe o ga oo
Agbe o ga
Iwo ti gbe soke wa n be lowo re
Agbe o ga o Olorun ife
Iwo ti gbe soke wa n be lowo re
Agbe o ga oo
Agbe o ga
Iwo ti gbe soke wa n be lowo re
Mo gbe o ga ooo
Ose Olodumare oo

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar