Kishore Kumar Hits

Tope Alabi - Mimo Oba Ara şarkı sözleri

Sanatçı: Tope Alabi

albüm: Igbowo Eda


Mimo ni oluwa oba ara
Ninu ogo re
Mimo ni, mimo ni oluwa emole
Oninu funfun, alaya funfun
Mimo ni oluwa oba ara, ninu ogo re
Mimo ni, mimo ni oluwa emole
Oninu funfun, alaya funfun
Abi saju awon oke
Otiwa saju awon ogun, owo re ni ofi no orun ja
Ohun gbogbo to da lo dara
Eda gbogbo, ewa juba ni etere, e teriba fun oba mimo
Oba aramanda ni
(Mimo ni oluwa oba ara ninu ogo re) ki gbogbo eda juba oo
(Mimo ni, mimo ni oluwa emole) iguwaorun, ite alayisi
(Oninu funfun, alaya funfun)
Mimo ni aluwa oba ara) mimo, mimo, mimo o
(Mimo ni, mimo ni oluwa emole) mimo to soju awon agbagba lojojo gbogbo
(Mimo ni oluwa alaya funfun) ko si eni to dabi owun oo
Ninu ogo to fi ojojumo ton lo gbe
Imole ti ki n ki, ojo de ojo ko yi pada
Eto alai le gbe, tawon eda orun bo
Orin Ako o da lenu won
Mimo ni won ko si
Ise Ade oo
(Mimo ni oluwa, oba ara) ishi I te o
(Ninu ogo re, mimo ni) to awon agbagba shi Ade fun
(Oninu funfun, alaya funfun) mo gbe fun e o
(Mimo ni oluwa oba ara) ido bale ni wowa ni mo pa kurukuru, olodu
Are oko eda
Funfun gbalawo, ki n se egbe ejon owo
Elewu funfun Nene
To to no ogo yin rin yin rin
Agba la gba ojo to yin gbo tio gbeje aye ya re
Odon tun-tun, onidun tun-tun
Mimo o, mimo o, mimo o, mimo o, fun oba mimo
Dagba orun
Owun ni dagba orun, alaye luwa, alorun luwa
Imole o, oninu funfun, alaya funfun
Mimo ni o oluwa wa, mimo ni o aseda imo
Mimo ni ade, mimo ni ite
Mimo ni oju, mimo ni ara
Mimo ni ogo ite rabande
Mimo ni ogogoju awon agbagba
Mimo ti awon oba orun o le sa ka we
Ekun wa mimo Nene lai laba won ara oto
Mimoi tawon eda orun ba ori won fun
Oba mimo, alai ni ika, ayi lojo
Arugbo ojo, kamomo-kamomo
To fin ojo ju mo ton I mole aramanda
Oni mo julo, olu Inu, imo ode, ijinle atudi, oro nla
I wo San ati iye, oba to ba Lori ohun gbogbo
Baába
Ko ni le ni ko to ba ni, Baába
Baba to ba Lori aye, Baába
Baba to ba Lori awon orun
Olu to bo ori ohun gbogbo, oni ye
Abo, onise so nu tio se kakaki olodumara o wa ye ri
Oba mimo, o se adarimu fi se fere
Tin tiInu eda jade bi eyon
Mo se bare, oba sioni
Ogagun, olugun, ite re ko le shi lailai
Oba to mo gberegbede
Ayi pako da, tin fi ojujumo tan imo ara
Mimo ni oluwa imole, oninu funfun alaya funfun

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar