Nigeria orile de abi mi Dide nle o Ko wa gba aare ee e Nigeria o orile de abi mi Dide nle o Ko ko igboji gbare gbare Oya gbare Baba iwo o la kepe Baba iwo o la ke si Baba iwo o la kepe Baba ti wa ma dowo re (Iwo la ke si o) Baba iwo o lakepe Baba iwo o lake si Baba iwo o lake pe Baba ti wa ma dowo re Oju re o lami wo o baba Orile de Nigeria Ti gbo ominira tipe Afe ominira lowo re o baba Eniti o batu sile Owun lo yege Baba jo o oluwa iwo lawa Kepe ye gbawa o Baba iwo o la kepe Baba iwo o la ke si Baba iwo o la kepe Baba ti wa ma dowo re Olowo pariwo mekunu Fi igbe bo nu To ba lo be ki Laye awon omo yio tiri Oun ti o fi fun wa o O to wa pin o kari kari O ri ba to lon Fowo ago seyin o Baba gba wa o olu orun Iwo lakepe iwo lo le yio ni lofin Baba iwo o la kepe Baba iwo o la ke si Baba iwo o la kepe Baba ti wa ma dowo re To ba gbawa ko si Eni a ma ke ba A kuku ti bo orisa A seleya esin gbogbo Sibe sibe unse lo le koko Ati sa ko lo de o Baba iwo lo to wa gbawa o Ogun idile lototo Afowo fa lo berebe To ba ta ro ese La o jiya a o segbe Eleyin ju anu iwo lakepe o Siju anu wo ori le de Nigeria Baba iwo o la kepe Baba iwo o la ke si Baba iwo o la kepe Baba ti wa ma dowo re Oh God of creation Direct our noble course Guide our leader's right Help our youth The truth to know In love and honesty to grow And living just and true Great lofty height attain To build a nation where peace And justice shall reign Baba iwo o la kepe Baba iwo o la ke si Baba iwo o la kepe Baba ti wa ma dowo re Let us all pray For the peace of Nigeria For those who love her prosper May there be peace And safety in your four corners I say to you peace be with you By the prayers of the saints Nigeria you are exalted Baba iwo o la kepe Baba iwo o la ke si Baba iwo o la kepe Baba ti wa ma dowo re Baba iwo o lakepe Baba iwo o lake si Baba iwo o lake pe Baba ti wa ma dowo re Gbogbo omo Nigeria E gbadura fun Eyin na e o se rere Gbogbo ijo omo olorun E toro fun anu Olori ijo ati Oluso aguntan e ma se dake Nigeria a wure fun o Ire ta su fun o yio se amin