Kishore Kumar Hits

Yinka Ayefele - Baba Pami Lerin Ayo (My Aspiration) şarkı sözleri

Sanatçı: Yinka Ayefele

albüm: Aspiration

Baba pá mí l'ẹrin ayo, kín le yin ọ l'ogo
Ohun t'aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenu
Ọba onile Ayo, ọba Atorise
Baba pá mí l'ẹrin ayo kín le yin é logo
Ohun t'aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenu
Ọba onile Ayo, ọba Atorise
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi

Airi na àìrí o aiye, baba mi kuro l'ọna

Airi na airi ibi aiye baba mu kuro l'ọna

Keṣu wa ribi ko subu ni waju mi o

Jeki satani ko subu ni waju mi o

Jẹ kí ọrọ mí dijo, jẹ kí ọrọ mí na sayo
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Jẹ kí ọrọ mí dijo, kí ọrọ mí ja sayo

Ohun t'aye ro pe ko ṣẹṣẹ ọlọrun wá bá mi ṣe o
Baba pá mí l'ẹrin ayo kín le yin ọ l'ogo
Ohun t'aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenu
Ọba onile Ayo, ọba Atorise
Baba pá mí l'ẹrin ayo kín le yin ọ l'ogo
Ohun t'aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenu
Ọba onile Ayo, ọba Atorise
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Jeki gbogbo ibi èsù já, mu ibi kuro l'ọna mi
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Jeki gbogbo ibi èsù já mu ibi kuro l'ọna mi
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Nipa agbara ẹjẹ Jesu ọlọrun wa ṣe ògo
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Nípa agbára eje Jesu ọlọrun wa ṣe ògo o

Jẹ kí ọrọ mí dijo ijo o
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Jẹki ọrọ mí dijo, ijo ayo ni t'emi
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Jeki oro mi dijo, fi oyin fadun sí ọrọ mí
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Ṣọrẹ ti ayé a ri pe ọlọrun ló ṣogò ayé mi o
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Ṣọrẹ ti ayé a ri pe ọlọrun ló ṣogò ayé mi o
Baba pá mí l'ẹrin ayo kín le yin ọ l'ogo
Ohun t'aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenu
Ọba onile Ayo, ọba Atorise
Baba pá mí l'ẹrin ayo kín le yin ọ l'ogo
Ohun t'aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenu
Ọba onile Ayo, ọba Atorise
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Airi na àìrí o aiye, baba mi kuro l'ọna
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Airi na airi ibi aiye baba mu kuro l'ọna
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Keṣu wa ribi ko subu ni waju mi o
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Jeki satani ko subu ni waju mi o
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Jẹ kí ọrọ mí dijo, kí ọrọ mí ja sayo
Ọlọrun bá mi gbórò, mi kí le ayé ma su mi
Ohun t'aye ro pe ko ṣẹṣẹ ọlọrun wá bá mi ṣe o
Baba pá mí l'ẹrin ayo kín le yin ọ l'ogo
Ohun t'aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenu
Ọba onile Ayo, ọba Atorise
Baba pá mí l'ẹrin ayo kín le yin ọ l'ogo
Ohun t'aye ro pe otí tan, bàbá ya won lenu
Ọba onile Ayo, ọba Atorise
Up Jesus, down Satan

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar