Kishore Kumar Hits

Yinka Ayefele - Idunnu şarkı sözleri

Sanatçı: Yinka Ayefele

albüm: Overcomer


Idunu subu l'ayo
Lo wole s'odo mi
Mo s'orire loni o, temi dara
Idunu subu l'ayo
Lo wole s'odo mi, yefele
Mo s'orire lo ni o, temi dara
Mo r'ohun to j'ayo, Jesu lo j'ayo lo
Mo r'ohun to j'ayo, Jesu lo j'ayo lo
Mo r'ohun to j'ayo, Jesu lo j'ayo lo
Mo r'ohun to j'ayo, Jesu lo j'ayo lo
Were o were, were o were lo bami se
Were o were, were o were lo bami se
Ohun ti mo ro, ti mo ro, ohun ti mo ro
Ohun ti mo ro pe ko sese, ko sese, ko sese,
Ko sese, were lo bami se
Were lo bami se, eh-e-eh, were lo bami se
Were lo bami se, eh-e-eh, were lo bami se
Ohun ti mo ro pe ko sese, were lo bami se
Ohun ti mo ro pe ko sese, were lo bami se
Were lo bami se, eh-e-eh, were lo bami se
Were lo bami se, eh-e-eh, were lo bami se
Ohun ti mo ro pe ko sese, were lo bami se
Ohun ti mo ro pe ko sese, were lo bami se
Oba awon oba, alagbara giga ooo
Oba lori aye
Oba awon oba, alagbara giga ooo
Ohun lo bami se
Ohun ti mo ro, ti mo ro, ohun ti mo ro
Ohun ti mo ro pe ko sese, ko sese, ko sese,
Ko sese, were lo bami se
Oba ni o ma je, eh-e-eh, oba ni o ma je
Oba ni o ma je, eh-e-eh, oba ni o ma je
Oba ta pe, to n fi'na da'hun, oba ni o ma je
Oba ta pe, to n fi'na da'hun, oba ni o ma je
Oba ni o ma je, eh-e-eh, oba ni o ma je
Oba ni o ma je, eh-e-eh, oba ni o ma je
Oba ta pe, to n fi'na da'hun, oba ni o ma je
Oba ta pe, to n fi'na da'hun, oba ni o ma je
E bami ki baba ku'se
Baba, baba, baba ku ise iyanu
Ani e bami ki baba po seun ooo
Baba, baba, baba ku ise iyanu
E bami ki baba ku'se
Baba, baba, baba ku ise iyanu
Mo ni e bami ki baba po seun ooo
Baba, baba, baba ku ise iyanu
Ijo kini n ba jo fun baba
Ara kini n ba da fun baba
Yinka, ijo kini n ba jo fun bami
Ara kini n ba da fun baba
Yefele, ma jijo owo otun boya a wu bami
Ara kini n ba da fun baba
Oya je a jijo owo alafia boya a wu bami
Ara kini n ba da fun baba
Mo ni, ijo kini n ba joooo
Ara kini n ba da fun baba
Eeeh mimo ni, mimo ni
Oba ti ko yi pada, iyin f'oruko re
Mimo ni, mimo mimo
E-eh, mimo ni, eeeh
Oba ti ko yi pada, iyin lo ye o ooo
Eeeh mimo ni, e-eh mimo ni
Oba ti ko yi pada, iyin lo ye o ooo
Mimo ni, mimo mimo mimo
E-eh, mimo ni
Oba ti ko yi pada, iyin lo ye o ooo
Oni l'ododo dajudaju, l'ododo dajudaju
L'ododo dajudaju, l'ododo dajudaju
Ah!, anu re yoo si wa titi aye
L'ododo dajudaju
Eh, ore ofe re yoo si wa titi lori mi
L'ododo dajudaju
Mo ni l'ododo titi lailai, l'ododo dajudaju
Ani l'ododo dajudaju ooo, l'ododo dajudaju
Anu re yoo si wa titi ooo
L'ododo dajudaju
Ore ofe re o si po ninu aye mi
L'ododo dajudaju
Eh, a j'oba, a j'oba
A j'oba, a d'ade ooo
Eni se gbagbo ooo, e ni s'eleya
A j'oba, a tun wa d'ade
A j'oba, a j'oba, ehh
A j'oba, a d'ade ooo, o sure
Eni se gbagbo ooo, e ni s'eleya
A j'oba, a d'ade ooo
Eh, a j'oba, a j'oba
A j'oba, a de wa d'ade ooo
Eni se gbagbo ooo, e ma ni s'eleya
A j'oba, a d'ade
A j'oba, a j'oba
A j'oba, a d'ade ooo
Eni se gbagbo ooo, e ni s'eleya
A j'oba, a d'ade ooo
Maa m'ayo dele ooo
Maa m'ayo dele ooo
Ori mi maa ma je n j'iya
Eda mi maa ma je n p'ofo
Maa m'ayo dele ooo
Maa m'ayo dele ooo
Maa m'ayo dele ooo
Ori mi maa ma je n j'iya
Eda mi maa ma je n p'ofo
Maa m'ayo dele ooo
Ko le baje ooo, ko le baje ooo
E ma le baje ooo, ko le baje ooo
Laye!, ise oluwa ko le baje ooo
Ise oluwa ah-a-ah, ko le baje ooo
Ko le baje ooo, ko le baje ooo
Laye!, ko le baje ooo, ko le baje ooo
Ah, Ise oluwa ah-ah, ko le baje ooo
Ise oluwa ah-a-ah, ko le baje ooo
Ijoba orun lere oni'gbagbo ooo
Ijoba orun n-n-n lere oni'gbagbo ooo
Ma je n kuna baba, mu mi dele ooo
Ki n ma ku s'ona bi efi, mu mi dele ooo
Aye l'oja orun n'ile, mu mi dele ooo baba
Ijoba orun lere oni'gbagbo ooo
Ijoba orun n-n-n lere oni'gbagbo ooo
Ma je n kuna baba, mu mi dele ooo
Ki n ma ko s'ona bi efi, mu mi dele ooo
Aye l'oja orun n'ile, mu mi dele ooo baba

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar