Kishore Kumar Hits

Yinka Ayefele - Thanksgiving şarkı sözleri

Sanatçı: Yinka Ayefele

albüm: Fresh Glory


Che che che che
Egbe ehn
Dr groove, o n womi
Ma womi o
Egbe
Alright now
Modupe ona ti Olorun gba, ota ro mi pin ni
Aráyé ẹwà bami yo o, èsù ti kabukun
Ọpẹ iyin ati ogo ma ni fún bàbá wa
Araye ẹwà bami yo o, kajo yo ṣẹṣẹ
Mo mu ọpẹ mi wa o eh eh
Mo mu ọpẹ mi wa ṣe eh eh
Mo mu ọpẹ mi wa o eh eh
Mo mu ọpẹ mi wa ṣe eh eh
Olore adaida t'emi ope mi eh
Olore adaida t'emi ope mi eh
Mo mu ọpẹ mi wa o eh eh
Mo mu ọpẹ mi wa ṣe eh eh
Mo mu ọpẹ mi wa o eh eh
Mo mu ọpẹ mi wa ṣe eh eh
Olore adaida t'emi ope mi eh
Olore adaida t'emi sha lope mi eh
Ijo eda ah ah
Orin àti ilu ati ijó Jesu
Ni mo fin yin oluwa
Lonile Lalejo kajo yo ṣẹṣẹ
Arúgbó ati ewe ka fi ijo yin baba
Tori ona to gbe oro mi gba gan
Lesu fún kabukun
Tori é, ti ti ti ti ti Aye mi
Lémi o yin baba
Ona to gbe oro mi gba gan
Lesu fi kan ijongbon
Ọpẹ iyin ati ogo ni fún ọ o
Ijo é da, oya roll it
Eje ka yin oluwa eh eh
Eje ka yin baba mimọ eh eh
Eje ka yin oluwa eh eh
Eje ka yin baba mimọ eh eh
Jesu mi Seun réré nínú ayé mi eje ka yin baba mimọ
Jesu mi Seun réré nínú ayé mi eje ka yin baba eh
Ka yin baba o eh eh
Ka yin baba mimọ eh eh
Eje ka yin baba o eh eh
Eje ka yin baba mimọ eh eh
Jesu mi Seun réré nínú ayé wa eje ka jo fo fún ayo
Jesu mi Seun réré nínú ayé wa eje ka yo o
Eho iyo Ayo si ọlọrun
Eyin orilẹ gbogbo, efi ayo sìn ọlọrun
Ẹwà ti ewe ti oyin sí waju re
Ke re le na fowuro ọlọrun
Ohun rẹ ẹda eni
Sede ri t'awa, awa ni eniyan re
Ati aguntan papa re
Elo sí ònà re tere ti ọpẹ
Ati se agbale re tere ti iyin
Ema dupe fún kede ma fi ibukún fún orúkọ rẹ
Torípé ọlọrun pọ ni ore re
Anu rẹ ni ipẹkun ati otitọ re
Lati iran di iran amin
Oti ya
Eje ka yin oluwa eh eh
Eje ka yin baba mimọ eh eh
Eje ka yin oluwa eh eh
Eje ka yin baba mimọ eh eh
Jesu mi Seun réré nínú ayé mi eje ka yin baba mimọ
Jesu mi Seun réré nínú ayé mi eje ka yin baba eh
Ka yin baba o eh eh
Ka yin baba mimọ eh eh
Eje ka yin baba o eh eh
Eje ka yin baba mimọ eh eh
Jesu mi Seun réré nínú ayé wa eje ka jo fo fún ayo
Jesu mi Seun réré nínú ayé wa eje ka yo o
Eho iyin ayo sí olùwà
Ihunle gbogbo, ife ayo sí olùwà
Iwati iti orin sí waju re ki n Mope oluwa
Ohun ni ọlọrun ohun ni òdà
Tire ni wa, iyanu egunre ati aguntan papa re
Ilo sí ẹnu ọnà rẹ titi ọpẹ
Ati iṣẹ igbala rẹ titi iyin
Mi ma dupẹ fún kín sì má fi ibukún fún orúkọ rẹ
Nitori oluwa pọ lore rẹ
Anu rẹ lapekun
Ati otitọ rẹ, lati iran di iran
Eje ka yin oluwa eh eh
Eje ka yin baba mimọ eh eh
Eje ka yin oluwa eh eh
Eje ka yin baba mimọ eh eh
Jesu mi Seun réré nínú ayé mi eje ka yin baba mimọ
Jesu mi Seun réré nínú ayé mi eje ka yin baba eh
Ka yin baba o eh eh
Ka yin baba mimọ eh eh
Eje ka yin baba o eh eh
Eje ka yin baba mimọ eh eh
Jesu mi Seun réré nínú ayé wa eje ka jo fo fún ayo
Jesu mi Seun réré nínú ayé wa eje ka yo o

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar