Kishore Kumar Hits

Yinka Ayefele - Iyin Ati Ope şarkı sözleri

Sanatçı: Yinka Ayefele

albüm: Living Testimony

Follow me
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ope, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
Follow me
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
Baba mimo, modupe lodo re Iwo lo ṣe
Baba mimo, modupe lodo re iwo ni o
Baba mimo, modupe lodo re Iwo lo ṣé
Baba mimo, modupe lodo re iwo mo mo
Ota n sáré pe nibo ni ma gbórò mi gba laye
Igba tan pe o tan, ọlọrun mi iwọ lo sope o ku o
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
Iyin ati ope o
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ o
Everywhere we go, we always give God the praise
Even when we dance, people think say we craze
We give the lord praise for everything he has done
For your grace and mercy and your reg forever
Ope, ope, ope, ope ni f'oluwa bàbá mimọ
Asèdá orun, ohun aiye ore re sí mi opọọ' o
Ore re sí mi opọọ' o ko lafiwe, alagbara
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
Iyo iyo iyo é
Iyo iyo iyo é
É é é é é é
Iwo nikan lémi o ma yin
Iwo nikan lémi o ma gbe ga
Tori iwo nikan la alagbawi
Jésù ọsẹ oluwa mi
I give praise to the mighty God
Titi ayérayé o Iwo lémi o ma yin
Mimọ mimọ mimọ mo gbe ọ ga
Lori aiye mi, lori iṣẹ mi o o o
Baba ọsẹ o tori pe
Ota n sáré pe nibo ni ma gbórò mi gba laye
Igba tan pe o tan, ọlọrun mi iwọ lo sope o ku o
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
Iyin ati ope o o
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
O-o-o iyin ati ọpẹ, iyin ati ope fún bàbá wa mimọ
La la la la la la la

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar