Kishore Kumar Hits

Yinka Ayefele - Iranlowo Eda şarkı sözleri

Sanatçı: Yinka Ayefele

albüm: Living Testimony


Aji aji aji aji aji aji aji ajigijigiji
Aji aji ajigijigiji
Aji aji ajigijigiji
Otí pe to, olùwà moni otí pe to
Otí pe to se, olùwà moni otí pe to se
Emi w'oju rẹ baba, dami lohun ayo
Emi w'oju rẹ baba, dakun ko fún mi l'esi ayo
Mo n w'oju rẹ
Iranlọwọ eda koto
Omo Olorun ran mi lowo o
Iranlọwọ eda koto
Omo Olorun saanu funmi
Iranlọwọ eda koto
Ọlọrun wa gbé bí mi já
Iranlọwọ eda koto
Omo Olorun saanu funmi
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun anu rẹ baba
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun anu rẹ baba
Kaye le mo mimọ ọ sí
Ki wọn lè mọ pe o tobi gan
Kaye le mo mimọ ṣilẹkun anu rẹ
K'arayé le mo mimọ ọ sí
Ki wọn si mọ pe o tobi gan
K'arayé le mo, k'arayé le mo
K'ayé le mo ṣilẹkun re
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun anu rẹ baba
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun anu rẹ baba
Tete ṣe o baba mimọ, fi adun s'aye mi
Olorun mi tètè ṣe o baba rere
Kò fi ọrọ mí ṣe iyanu sì
Tete wa ṣe o baba mimọ, fi adun s'aye mi o
Ọlọrun mi tètè ṣe o baba rere
Ko fi ọrọ mí ṣe iyanu sì
Ṣilẹkun ṣilẹkun ṣilẹkun anu rẹ baba
Ṣilẹkun ṣilẹkun ko fi ọrọ mí ṣe iyanu sì
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun anu rẹ baba
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun anu rẹ baba
Ọpẹ ti mo tin w'oju rẹ baba ṣilẹkun anu rẹ
Ọpẹ ti mo tin gbadura o ṣilẹkun anu rẹ
Ọpẹ ti mo tin w'oju rẹ baba ṣilẹkun anu rẹ
Ọde pẹ ti mo tin gbadura o ṣilẹkun anu rẹ
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ìyí ayé tó tẹ
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ona ayo mi
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun anu rẹ baba
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun anu rẹ baba
Oju sanmọ dudu ahh okunkun bole
Itori ta meta re tin da'mu Aye o
Mo duro, mo ro, mo bere mo ro
Bi Mosun ma ro, sibe ko dé ye mi mo rara
Moti bere, emi si ti kan lẹkun
Moti wa kiri dé lè é o
Àní moti bere, emi si ti kan lẹkun
Moti wa kiri dé ọdọ rẹ
So ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun ṣilẹkun
Ṣilẹkun ṣilẹkun, ṣilẹkun anu rẹ
Fi ire mi le mi lọwọ, fi ire mi le mi lọwọ
Ọlọrun mi f'ire mi le mi lọwọ
Maje ki ọta bere pe ọlọrun mi da
Fi ire mi le mi lọwọ, fi ire mi le mi lọwọ
Ọlọrun mi f'ire mi le mi lọwọ
Maje ki ọta pe jọ sí ọdọ mi
Iranlọwọ eda koto
Omo Olorun ran mi lowo o
Iranlọwọ eda koto
Omo Olorun saanu funmi
Iranlọwọ eda koto
Ọlọrun wa gbé bí mi já
Iranlọwọ eda koto
Omo Olorun saanu funmi
Iranlọwọ eda koto
Omo Olorun saanu funmi
Iranlọwọ eda koto
Omo Olorun saanu funmi

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar