Kishore Kumar Hits

Victor Olaiya - Opataricious (Victor Olaiya's Incantation) şarkı sözleri

Sanatçı: Victor Olaiya

albüm: 51 Lex Presents Okwudili


Eni deru leru nto
Elete lete nye
Oun taba ti shey ni n yeni
A kii gba akata lowo akiti
A kii gba ile baba eni lowo eni
Ahere ni yo keyin oko
Atan ni yo keyin ile
Imado iba shey bi elede a ba ile je
Eru iba je oba eniyan o ba ti ku ikan
A kii ru eran leri ka ma fi ese ta ere nle
Seke ko mo eni oba
Ojo ko mo eni owo
Oun ti a ba so siwaju ni a nba
Oun ti a ba ti gbin seyin ni aowa
Igba ti a o so siwaju
Tao gbin seyin
Kini a o ba
Mtcheew, Ose ni saaju ekun
Abamo ni gbeyin oro
Gbogbo oto ilu pe
Won ko ri ebo abamo se
Mura si ise ore mi
Ise ni a fin deni giga
Bi a ko ba ti ri eni feyinti
Bi ole laari
Bangboye, bi a ko ba ti reni gbekele
A tera mo'se eni
Iya re le lowo lowo
Ki baba lesin leekan
Ah, ti o ba gboju lewon
O te tan ni m o so fun o
Iya nbo fun omo ti ko gbon
Ekun nbe fun omo tin sa kiri
Ma fi owuro sere ore mi
Opataricious
Opataricious
Opataricious
Opataricious
Opataricious
Opataricious
Opataricious
Opataricious
Opataricious
Opataricious
Opataricious

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar