Mafi Kan Won Wa Ninu meta Alafia owo pelu omo won dun ni Mafi Kan Won Wa Ninu meta Mafi Kan Won Wa Ninu meta Alafia owo pelu omo won dun ni Akoko ti aba ti ni alafia Owo ade bowo de omo ade Akoko ti aba ti ni alafia o Owo ade bowo de omo ade Bi Kan osi ninu meta Kobosi rara afi ti meta ba pe Bi Kan osi ninu meta Kobosi rara afi ti meta ba pe Iru aye ti kaluku wa Eteti egbo ge bi won ti je Alafia ni baba agba Toye kakoni kowo to de Alafia ni baba agba Toye kakoni kowo to de Omo lo siketa Gbogbo wa lo ma bimo ye Mo le tori omo jijo idunu odun kan Eni bimo ni o jogun aye mon wi Mafi Kan Won Wa Ninu meta Mafi Kan Won Wa Ninu meta Alafia owo pelu omo won dun ni Kosemani loruko omo omo mo sin omo lafe aye o Kosemani loruko omo omo Kosemani loruko omo omo mo sin omo lafe aye Ejowo bi osomo lewa Asan ni ki ama puro Ejowo bi osomo lewa o Asan ni ki ama puro Omo eni ni foto eni Omo eni ni foto eni Ti aba ma kira lode Won o ni bere pe owo nko Won o ni bere pe aso nko Awon somori wa mi à bere Wa so wipe se alafia lowa Ile nko Iyawo nko Se dada lomo nbe nile Iyen lomu mi ranti wi pe Alafia legbon ninu meteta Owo owo la fin tomo Ni to o to olomo lojo gun aye Kosemani loruko omo omo o Kosemani loruko omo omo mo sin omo lafe aye o Mamaje apasan oluwa fun wa lomo aridunu lan bebe o Mamaje apasan oluwa Mamaje apasan oluwa fun wa lomo aridunu lan bebe o Omo ti o kawe re koleji ti o deniyan nla ni ko fun wa bi Omo ti o kawe re koleji ti o deniyan nla ni ko fun wa bi Omo to ma gbe mama niyi da mama lola lawa ntoro Abe e oluwa nile aye nbi