Kishore Kumar Hits

Teledalase - ILÉ KOKO şarkı sözleri

Sanatçı: Teledalase

albüm: ILÉ KOKO


Omo kekere mo sokele
Agbalagba mo sokele o
Mo ti doyo
Oyo alaafin
Mo ti dosogbo
Osogbo ilu aro
Mo ro Oluode
Mo wa Iya mi lo
Won ni Iya mi n be ni Sabo
Mo rekete
Mo sa fejo
Olowo laye n fe
Mo rekete
Mo sa fejo
Olowo laye n fe
Nba ti mo
Nba ma ti lo o
Nba duro sile
Nba ti mo
Nba ma lo o
Nba duro sile
Ile o o o o
Ile o o o o
Ile Koko n tagbe
Tagbe
Ile o o o o
Ile o o o o
Ile Koko n tagbe
Tagbe
Mo de Sabo
Sabo mo n wa Iya mi
Won n re oloke meji
Iragbiji oloke meji
Tako tabo loro agba
Mo n lo
Kabiesi
Mo dele Aresa
Omo feni si
Ni n bi Iresa nu
Won lomo tani mi o
Mo lomo Aresa ni mi
Nba ti mo
Nba ma lo o
Nba duro sile
Ile o o o o
Ile o o o o
Ile koko koko n tagbe
Tagbe
Ile o o o o
Ile o o o o
Ile Koko n tagbe
Tagbe
Emi lomo Aresa
Omo feni si
Ni n bi Iresa nu
Wole o bupo ya mi o
Ya mi o
Ile Koko n tagbe
Tagbe
Mo de Ikole
Mo n bere Iya mi
Oba loni ka rogi laso
Nba ti mo
Nba mati lo o
Nba duro sile
Ile o o o o
Ile o o o o
Ile koko koko
N tagbe tagbe

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar