Kishore Kumar Hits

Asake - What's Up My G şarkı sözleri

Sanatçı: Asake

albüm: Work Of Art


(Tune into the king of sound and blues)
Mr. Money with the vibe 'til the devil say my name
Ibẹ l'owa, mo ní, ibẹ ló ńgbé
Ogedengbe, kí ló dé t'olọ gbé?
Abena, ṣébí Accra lóń gbé
Ṣ'ọmọ 2:30 for the pool party
Full branding, no be fugazi
White Range and black Maserati
We dey fire go, kòní dá fún anybody
Wọn ní wọn fẹ lé wá, àápẹ, k'ọto rí wá
My pretty Jemila, Angelina
High me sensimilla
Olómi, jogor, k'owa
Mo ní, what's up, my G?
I'm young, wild, and free
I spend money like young alhaji
But, I be big alhaji, pẹ'lú Ghazi, my G
Ó to'jọ' mẹ'ta tí mo ti jọn
Baby, I never chop
Ṣé'di l'oro m'aṣọ àbí aṣọ l'oro mọ'di?
Modina, góńgó asọ
Do, re, mi, fa, so, ọmọ, the dance floor
Scatter when I sing my song
Mr. Money, dá'jọ, ọmọ, wey my mullah?
Ẹ má f'owó mí da'jọ
Gucci, Louis V, f'owó rà designer
Akube kọ, no be China
Or'ajé l'ọ'wọ' mí, olooṣáka, final
Akuaba, skelewu, are you from Ghana?
Seen many girls but my baby finer
Oh Nana, ọmọ tó ṣàn bí Rihanna
Baby, go down now, no gimme wàhálà o
Baby, ma jẹ k'ìlékẹ yẹn kó já now o, kasa
Wàhálà o, wàhálà o, I dey para, para o
Ọmọ, wa now, wa now o
K'ama jammer oh
Ọmọ ọlọpẹ tí hammer o
Ò yẹ k'ama sama oh
Àgbà ní t'ara
No go kill me, Johanna
Oya, give me jara o
O lè barawo
She wan give me sangalo
Ọmọ, e no easy, yawo o
Wọn ní wọn fẹ lé wá, àápẹ, k'oto rí wá
My pretty Jemila, Angelina
High me sensimilla
Olómi, jogor, k'owa
Mo ní, what's up, my G?
I'm young, wild, and free
I spend money like young alhaji
But, I be big alhaji, pẹ'lú Ghazi, my G
Ó to'jọ' mẹ'ta tí mo ti jọn
Baby, I never chop
Ṣé'di l'oro m'aṣọ àbí aṣọ l'oro mọ'di?
Modina, góńgó asọ
Do, re, mi, fa, so, ọmọ, the dance floor
Scatter when I sing my song
Mr. Money, dá'jọ, ọmọ, wey my mullah?
Ẹ má f'owó mí da'jọ
Gucci, Louis V, f'owó rà designer
Akube kọ, no be China
Or'ajé l'ọ'wọ' mí, olooṣáka, final
Akuaba, skelewu, are you from Ghana?
Seen many girls but my baby finer
Oh Nana, ọmọ tó ṣàn bí Rihanna
Baby, go down now, no gimme wàhálà o
Baby, ma jẹ k'ìlékẹ yẹn kó já now o, kasa

(Tune into the king of sound and blues)

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar