Mo kí rá fun Ọba Ilayi Tí o dójú tí mí o Ko sí ẹní t'omọ là t'oko Ẹ'mí náà àá d'eyán o Ẹlẹ'dàá mí má jẹ rá m'àyé Ehhh, mo tí dé bí mo ṣe ńdé o Mo tún-tún gbé èrè mí dé o Oluwaloseyi o Ẹní fẹ ná mí owó o kó wa bí Bisi-Bisi, ní wo yí? (ní wo yí?) Sexy Mama, ní mà yí (ní mà yí) Ṣé o má lo mọ singer yí (singer yí) Everyday ká ní bà yí (ní bà yí) Àwọn kàn tí kó ṣí wàju, wọn tún kó'rin ni sí yín o Àwọn kàn wá pọ níwájú, Alabi o wesẹ mí o Bá mí kí Bàbá Balo Ẹní jẹun lo má yo Ìkú má pá brother mí o Kí ikú má pá maga mí o K'emí r'owó ṣayé Wọn gbọ mí ní Germany dé'Ibafo Kó mọ gbà t'owó kú wazo o Àwọn girl tí wo Palazzo Óyà, baby mí, wá jo O tí mọ p'owó dé kún'lé o 50 Million ẹ-ku wazo Money dey tí má ká o Seyi, Malaika Àwọn kán fẹ gará ní massion o When I say óyá-óyà, let's dance Óyá-óyà, jẹ ká jo Óyá-óyà, let us dance Jẹ ká lo s'agbo Loseyi oo Óyá-óyà, let's dance Óyá-óyà, jẹ ká jo Óyá-óyà, let us dance Jẹ ká lọ s'agbo Loseyi oo Óyá-óyà, let's dance Óyá-óyà, jẹ ká jo Óyá-óyà, let us dance Jẹ ká lọ s'agbo Loseyi oo Óyá-óyà, let's dance Óyá-óyà, jẹ ká jo Óyá-óyà, let us dance Jẹ ká lọ s'agbo Loseyi oo ♪ Woo!