Lo kede Ayo, Oluwa ran o Bi agutan s'arin ikoko aiye Gbe fitila iyin rere (Percussion display) Dide tan mole ayo Ogo Oluwa yio yo lara re Wi fun Jesu wipe emi niyin ran mi Iroyin ayo so t'irapada f'araye Lead 1 Iroyin ayo ni fun gbogbo eda Wipe Jesu joba lori gbogbo aiye A o da o nide, a o fi ayo de o lade Jesu yio yo si o pelu owo itura re Lead 2 Ore faramo Jesu Ojo... aiye yi nlo bi afefe T nrekoja, to ko si yi pada rara Iba dara ko pese fun le re loke orun Gboju re soke wo rawo didan To nso t'ife Olorun Wipe bo ti wu kiji aiye le to Owo agbara Oluwa yio da duro Gbo Ohun alore, ji ara ji Jesu ma fere de, ji ara ji Omo oru ki nsun Omo imole leyin Ti nyin logo didan, ji ara ji Ji, iwo okan mi Ji o, ko orin iyin Korin ayo, gbohun ayo s'oke o Si Baba, eleruniyin E gbe laruge, e so t'ife re si eniyan Bi Baba ba nbinu, aiye iba ti f'aya O fi omo bibi re s'etutu f'ese wa Se rere o omo, Baba nreti re (Interlude... Jesu npe wa losan loru) Oro Oluwa lo nwipe Awon to gbekele Oluwa Yio dabi oke sioni to duro lailai A o tun agbara mi se Bi mo sare ko ni re mi Wun o rin are kan ko ni si A o b'omirin irugbin mi Wun o fi iye fo bi idi Ninu ayo owo agbara igbala (Percussion Display) Call: Ta lo nkan lekun okan mi Res: Jesu Alagbara, Jesu Atobiju Call: Ta lo wo mi laso iye Oba to segun iku Alade Alafia O di igbekun ni igbekun lo O gba ebun rere fun mi o O mba mi gbe nigbagbogbo, mo gbo ohun re nitosi o Amona at'oluto mi loje Ti ko ni f'asiri mi han O nfi ilera fun okan mi Mo fe O edidi ife O f'ounje iye bo mi O nfun mi l'omi iye mu Ta lo le mu mi rerin ayo, To mba mi s'ore otito Alagbawi mi loke o, wa de mi lade ogo End