Kishore Kumar Hits

King Sunny Ade - Moti Mo - Live şarkı sözleri

Sanatçı: King Sunny Ade

albüm: Live Live Juju


Mo de o baba
Mo wa sope Ore nla
Baba ti gba awon Omo e
O tunminu
Ebami dupe f'oluwa to ranmilowo
Baba gba mi lowo isubu at'omije
Kini on'fi fun oluwa fun Ore re
Ope mi pe'lesin mi o tunmininu
Mo ti da majemu o e
Un o San majemu mi o a
Fun baba olore ofe
To se'leri to muse o a
Mo de o baba
Mo wa sope Ore nla
Baba ti gba awon Omo e
O tunminu
Ebami dupe f'oluwa to ranmilowo
Baba gba mi lowo isubu at'omije
Kini on'fi fun oluwa fun Ore re
Ope mi pe'lesin mi o tunmininu
Mo ti da majemu o e
Un o San majemu mi o a
Fun baba olore ofe
To se'leri to muse o a
Ore Ofe lo da mi si
Mo mo ye na
Mo d'olola loju ota mi o Emi ajo
Iku fo lo arun segbe o - eyi tope
Baba Wole eti odo mi o ranmilowo
Eba mi Jo eyin ara mi ile aye
Kope yi o ko wa ka la n toro
Mo ti da majemu o e
Un o San majemu mi o a
Fun baba olore ofe
To se'leri to muse o a

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar