Kishore Kumar Hits

Oladips - Escolopidium - (Funwonje) şarkı sözleri

Sanatçı: Oladips

albüm: Escolopidium - (Funwonje)

Yor-yor, yor, ahn-ahn
Moti kor hip-hop, moti kor reggae
Odayan mo, ola emi kor yeye
Beremi lowo awon ton tin gbọ tey-tey
Ata awon morufa idigan l'ebe
Bíi moo shey funwon, lon pariwo Chineke
Faluya funwon bíi Sunny Nnweke
Oromo Adiye, Asha Suregbe
Environmental, awa tunlese
Emi lala gbé, eyin lele gbé
Emi lala dura, eyin lelepe
Eyi tatun bebe, otun peleke
Awon olorin wẹwẹwẹ, won tii ferege
(Eni òríyọ, Iyen tii jẹ home training pa)
(Talosope whyning, okin se fiipa)
(Won ni talo loyun too wa ninu abiba)
(Woo, Brother you fit ask ifa)
(Eni òríyọ, Iyen tii jẹ home training pa)
(Talosope whyning, okin se fiipa)
(Won ni talo loyun too wa ninu abiba)
(Woo, brother you fit ask ifa)
Anytime wey I pull up
Wọn máa kuu lọ oya s'ope o'tilọ, o'tilọ jor
Them they ask make I do more ya-ya-ya
Anytime wey I pull up
Wọn máa kuu lọ oya s'ope o'tilọ, o'tilọ seh
Them they ask make I do more ya-ya-ya
(Ola funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa jẹ jor, koo to) escolopidium
(Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, oya s'ope o'tilọ) escolopidium
(Ola funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa jẹ jor, koo to) escolopidium
(Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, oya s'ope o'tilọ) escolopidium
Wizzy be like person wey don take banku
He dey carry them trabaye
Bawo lon shey shey ee ṣàlàyé
Ọmọ tẹti fojú dii yen mamare
Moo ti fobo gan, motion gbogbọn gan
Motii fobo gan Moti lọwọ kan
Salawa break my heart, moo dẹ fii ṣọkan
Moti showo kan, kọ tóo fii f'okọ
Moní gangan sọ, lọ multi Sponsor
Bíi ajey tẹ R2, lòó Shege tẹ cursor
Emi ọmọ ton sọ, too tun taa san san
Ọwọ tóo fii fọ ata,.má fii fobo pọn
(Eni òríyọ, Iyen tii jẹ home training pa)
(Talosope whyning, okin se fiipa)
(Won ni talo loyun too wa ninu abiba)
(Woo, Brother you fit ask ifa)
(Eni òríyọ, Iyen tii jẹ home training pa)
(Talosope whyning, Okin se fiipa)
(Won ni talo loyun too wa ninu abiba)
(Woo, Brother you fit ask ifa)
Anytime wey I pull up
Wọn máa kuu lọ oya s'ope o'tilọ (o'tilọ jor)
Them they ask make I do More ya-ya-ya
Anytime wey I pull up
Wọn máa kuu lọ oya s'ope o'tilọ (o'tilọ seh)
Them they ask make I do More yayaya
(Ola funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa jẹ jor, koo to) escolopidium
(Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, Oya s'ope o'tilọ) escolopidium

(Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, Oya s'ope o'tilọ)
(Ola funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa jẹ jor, koo to) escolopidium
(Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, Oya s'ope o'tilọ) escolopidium
You dey use your future to play
You dey use your generation to play
You dey use your next generation to play
You are doing rubbish, the things dar you are doing good
You are doing lunatic, lunatic escolopidium
Picaluculation of Jijatical

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar