Maja Maja Maja Maja Maja Maja If dem no open door for me, e mi aja lekun Maja maja maja o If dem no open door for me, e mi aja lekun yi, o Maja maja maja o Yeah Young makanki, I dey para Young makanaki, I dey crase I go change am for anybody Anybody wey try to stop me This big apple, I go chop am o This little light of mine, I'm gon let it shine Trouble dey, but I go conquer Maja maja maja Tẹ'níọlá, Ọmọ Simeon, Ọmọ Ọláṣebìkan Ọmọ J'ọ'gẹ'dẹ' sunwọ'n ju onisu Ọmọ ọ'gẹ'dẹ' lílá aborí kìjọkìjọ Ọmọ Oká, Ọmọ Erè, Ọmọ Ọwá, Ọmọ Ẹkùn Ǹlẹ' ò Tẹ'níọlá Ó ró gẹ'gẹ' ó wọnú ẹgbẹ' Ẹ'gbọ'n Tẹjúmọ'lá Ọmọ Fọlájogún, Olúbi àrókẹ' Ǹlẹ' ò Ẹdúlamọ', Àrà dede ṣekùn Ùpọn kùkù súnlána ẹ' tímọ'tímọ' Í ké bá bayà un, í á bànà un Ọmọ ẹbọ díyé ẹwà ṣe úfẹ'ẹ' nanàá Ọmọ lúmọlẹ' yéye gidọnẹ Ọmọ Aládémèjì l'óǹdó Ọmọ aládé mù, ọmọ aládé udẹ Ọmọ ọlá oko àgbá jì yẹyẹ nínú ìṣà Ọmọ lẹ'gungun gbọ'n wéè àpò Ọmọ lílẹ'pọ'n bíi tadẹ'gbudọ' mú joi Nímọ'ṣà Ọmọ lúmọlẹ' Ọmọ lúmọ' ìṣà lúmọ', Ọmọ Ọláṣebìkan Ọmọ àtàkúmọ', Ọmọ lógo, Àólú Ọmọ énusọ'