Má yà 'lé mi ìwọ ọ'rẹ' àtojúbọ' onílé Má yà 'lé mi ìwọ ọ'rẹ' agbọk'ọlọ'kọ Má yà 'lé mi ìwọ ọ'rẹ' àdúgbò Má yà 'lé mi, má yà 'lé k'ọmọ Ọ'rẹ' tí mo mú bí àbúrò Ọ'rẹ', Ọ'rẹ' tí mo ṣe dáradára Ọ'rẹ' tí mo finú hàn Owá dà mí o, ó tú mi síta Ó dà bí ọ'rọ' àná Eh b'ọ'rọ' àná Don't come to my house Iwo ọ'rẹ' èké àdúgbò Don't come to my house Ìwọ ọ'rẹ' adalérú Má yà 'lé mi, ìwọ ọ'rẹ' kòfẹ'nifẹ're Má yà 'lé mi o, Má yà 'lé rara Ńṣe ni mo lọ wá lọ'jọ' yìí o Ọkọ tó fẹ'mi sí lé Kò kú lo wá'ṣẹ' ṣe Láwọn méjèèjì, wọ'n bẹ'rẹ' ìṣekúṣe Wọ'n ń hùwà ọmọdé Wọ'n ṣe bó ṣe wù wọ'n Ó dà bí ọ'rọ' àná Eh b'ọ'rọ' àná Eh dà bí ọ'rọ' àná Oh b'ọ'rọ' àná Ẹ wá wo ìjà lọ'jọ' yẹn Ẹ wá wo èrò tó ń tún tà Ẹ wá wo ẹ'jẹ' nílẹ' Ah ọ'rẹ', ọ'rẹ' o, o tú mi síta Má yà 'lé mi oh-oh-oh I don't wanna see you no more Má yà 'lé mi oh-oh Tẹ' máà béèrè mi n'lé Ah, má yà 'lé mi oh-oh I don't wanna see you no more Ọ'rẹ' ìṣé bùṣe k'ọ'wọ' rẹ o-o Èmi ò ti ẹ' lè pààyàn