Gbémi ṣán lẹ̀ Kó mi sí'ta Fàmí lẹ'wù ya Tẹ̀mí lọ́rùn pa Ènìyàn lásán ni mo jẹ́ Mo fú'yẹ́ bíi paper Ìjí jà lódò Ó gbémi lọ sóko Ẹ̀dùn ọkàn Òhun l'ọkọ̀ Gbé mi lọ síbi tó kàn Ògá tà ògá ò tà Ọlọ'ọ'pá gba rìbá kàsà Ẹ̀dùn ọkàn Òhun l'ọkọ̀ Gbé mi lọ ibi mò ń lọ Ẹ̀dùn ọkàn Fún mi lọ́kàn Ọkùnrin mẹ́ta dé'bi tí mò ń lọ ♪ Èmi ni ìmọ́lẹ̀ O ló'kùnkùn wọ gbó lọ Mo fà á lẹ́'wù ya Mo tẹ̀ l'ọ́rùn pa Ènìyàn lásán mi ò jẹ́ Mo wíwo bí ẹ̀san Èmi ni ìjì tó jà l'ódò Tó gb'ọba wọn lọ s'óko Ẹ̀dùn ọkàn Òhun l'ọkọ̀ Gbé mi lọ síbi tó kàn Ògá tà ògá ò tà Ọlọ'ọ'pá gba rìbá kàsà Ẹ̀dùn ọkàn Òhun l'ọkọ̀ Gbé mi lọ ibi mò ń lọ Ẹ̀dùn ọkàn Fún mi lọ́kàn Ọkùnrin mẹ́ta dé'bi tí mò ń lọ ♪ Ẹ̀dùn ọkàn Òhun l'ọkọ̀ Gbé mi lọ síbi tó kàn Ògá tà ògá ò tà Ọkùnrin mẹ́ta dé'bi tí mò n lọ