Kishore Kumar Hits

Qdot - Kokanmi şarkı sözleri

Sanatçı: Qdot

albüm: Alagbe


Òní wàràpá tí rọlú mágún (kasa!)
Kokanmi, kokanmi
Qdot lórúkọ mí (kokanmi, kokanmi)
Mo mọ pé mo mí lẹ́ ṣé ń f'ọbo lọmi
Mí o l'órí lo gùn pé ìbon ó lé rán mí
Bíbélì mọ ní pẹ'lú Qurani
Pẹ'lú kíní báàmí tó ń dùn woro-woro
Ẹní f'ojú dí iná, iná à jo
Ìyá Ìbàdàn, óyà, gb'àgbo lè 'ná
Èpò ọ'gẹ'dẹ' kò lé yó mí
Máapẹ bí Aláàfin Ọ'yọ' ní
We're' ní wọn mó má lé wọn s'Aro
Má gbé wọn lọ bí 'dò-dò Ìyá Aláró
Ẹ fún mí hammer, kín fọ wọn lórí ká
Àwọn we're', àwọn motherfucker
Ẹ ro dádá k'ẹto b'Èṣù lówé
Ẹ sọ fún Ṣígidi, kò má r'odò lọ wẹ
Kílóńjẹ' kò s'ewé, kò s'egbò nínú àyé?
K'Ọlọrun májẹ à rí'já àyé ní
Shi-o kelẹbẹ (kokanmi)
Wọn ní pé, "Picker die" (kokanmi)
Pé client ó sọrọ mọ (kokanmi)
Pé ìyàwó yín ń ṣé oloṣo (kokanmi)
Ó sún yàrá landlord (kokanmi)
Wọn fẹ mo'dí abájọ (kokanmi)
Taní bàbá alájọ? (Kokanmi)
Ẹ re ilé bàbálawo (kokanmi)
Ẹbọ yìn má fọ m'awo (kokanmi)
Wọni pé Yahoo ní (kokanmi)
Wọni pé à ṣ'ogun owó (kokanmi)
Òní wàràpá rọlú mágùn (kokanmi)
Pé Lagbaja b'ójú k'orin (kokanmi)
Ẹní òyìnbó ó dùn lẹ'nu mí (kokanmi)
But local mí ń ja'wó (kokanmi)
Òkè Kilimanjaro sọpé Olumo ó gá
Àgbọ' t'ajá, àgbọ' t'ẹran
Èwo ní t'àgùntàn lórí àga
Wọn ní mọ local, mo ń pa'wó lọ
Ọmọ Folashade, mo tí gba'dé lọ
Òyìnbó lé má dùn lẹ'nu mí
Èyí tí ń bá sọ, Wole Soyinka l'aba yìn tu
Ẹ wá wo èlékó tó yàn'dì s'oní moi-moi
Òní bùgan bínú ẹlẹ́wà àgóyìn
I don't care if you like or not
Ẹní ṣíṣẹ ló má pa'wó
Kòkòrò tó ń jó leba ònà ní, onílù re ń bẹ nínú igbó
Mó tí gòkè, mó tí ṣé lọ k'afara tó já
Mó japa, k'òyìnbó tó já
Ọmọdé àná tí wá d'àgbà
Qdot, ọmọ imalẹ afeleja
Ẹ ro dádá k'ẹto b'Èṣù lowe
Ẹ sọ fún Ṣígidi, kò má r'odò lọ wẹ
Kílóńjẹ' kò s'ewé, kò s'egbò nínú àyé?
K'Ọlọrun májẹ à rí'já àyé ní
Shi-o kelẹbẹ (kokanmi)
Wọn ní pé, "Picker die" (kokanmi)
Pé client ó sọrọ mọ (kokanmi)
Pé ìyàwó yín ń ṣé oloṣo (kokanmi)
Ó sún yàrá landlord (kokanmi)
Wọn fẹ mo'dí abájọ (kokanmi)
Taní bàbá alájọ? (Kokanmi)
Ẹ re ilé bàbálawo (kokanmi)
Ẹbọ yìn má fọ m'awo (kokanmi)
Wọni pé Yahoo ní (kokanmi)
Wọni pé à ṣ'ogun owó (kokanmi)
Òní wàràpá rọlú mágùn (kokanmi)
Pé Lagbaja b'ójú k'orin (kokanmi)
Ẹní òyìnbó ó dùn lẹ'nu mí (kokanmi)
But local mí ń ja'wó (kokanmi)
Jirafa jalika ra fali eli Malaika mí Orimolade
Ẹní f'ojú dí iná, iná à jo
Ìyá Ìbàdàn, óyà, gb'àgbo lè 'ná
Èpò ọ'gẹ'dẹ' kò lé yó mí
Máapẹ bí Aláàfin Ọ'yọ' ní
K Sir Sosse
King of Marley
Musa Felix for Garuba
Femi Jaguar nílùú London
Mo mọ Baddy Oosha
Lanre Typical
Milli ọmọ Salawe
Mo mọ Femi Chill Music
Mo mọ Billique (mo mọ Billi')
Mo mọ Doctor Brown
Mo mọ Arowolo, Arowolo tí ń tá motor
Mo mọ Bottles, IBD Dende
Aláṣẹ Nikas Teni Level
Motí mọ Water
Mo mọ Owo Mabo
Bunmi simple casher
Mo mọ Unique Motors
Mo mọ Climax
Mo mọ Pasuma Wonder, ọmọ ìyàwó Anọbi l'Omole
Xsmile
(Yeah, who's here?)
Quick as sure boys

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar