Kishore Kumar Hits

Qdot - Gbeja (feat. Alh. Wasiu Alabi Pasuma) şarkı sözleri

Sanatçı: Qdot

albüm: Alagbe

Pasuma wonder oh
Ìjọba Fuji oh
Bàbá Wasila
Daddy Rokiba
Qdot lórúko mí
(2T upon the beat)
Kòye wọn
Wọn fẹ mọ'di abájọ mí
Wọn fẹ mọ'lé bàbá alájọ mí
Ọ'tá fẹ mọ ìgi lẹ'yìn ogba mí
Wọn fẹ mọ'ye t'ówà ní ipamọ mí oh
Bàbá mí lókè ńpá mí mọ
Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Àdúrà lo ń gbà, àgbàrá ko (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Oṣó ń gb'ogun, ọ'tá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà)
Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà)
Ìṣẹdà mí, gbéjà mí jà (gbéjà)
Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà)
Ẹ jẹ kà dúpẹ' pé ènìyàn kò ló l'Ọlọrun wá
Kà lènìyàn ní, ènìyàn lé ní k'òjò má ro, sùgbọ'n
Àdúrà lógbà, àyé fẹ pá kádàrá mí dá, ṣùgbọ'n
Kín má wọ jersey, kín má wọ bootu
Penalty mí ó lé jẹ'rín
Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Àdúrà lo ń gbà, àgbàrá ko (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Oṣó ń gb'ogun, ọ'tá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà)
Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà)
Ìṣẹdà mí, gbéjà mí jà (gbéjà)
Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà)
Èmi lẹni t'ayé tí ro (t'ayé tí ròpìn oh)
Pé kólé dá ń kán 're ṣé o ('re ṣé o)
Ṣùgbọ'n, mó rí àánú ẹ gbà, Olú Ọ̀run o, lo bamiṣé oh (Alabi oh)
Wọn sáré, sáré, sáré
Olúwa júwọn lọ
Wọn gb'ero pé kó bàjẹ́ ní, orí mí ó gbàbọdé o (Pasu')
Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Àdúrà lo ń gbà àgbàrá ko (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Oṣó ń gb'ogun, ọ'tá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà)
Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà)
Ìṣẹdà mí gbéjà mí jà (gbéjà)
Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà)
Bàbá mí tí ṣé, Bàbá mí tí ṣé, Bàbá tí ṣé
Oùn t'aye rope kò ṣé-ṣé, Abaniṣe tí bámí ṣé
Òun tímo wá lọ Sokoto, o ń bẹ l'apo ṣòkòtò mí
Ọmọ tóní kólé pa'gan, ó ko'lé alarinrin
Àdúrà lógbà (àdúrà lógbà)
Àyé fẹ pá kádàrá mí dá, ṣùgbọ'n
Kín má wọ jersey, kín má wọ bootu
Penalty mí ó lé jẹ'rín
Wọn fẹ mọ'di abájọ mí (mọ'di abájọ mí)
Wọn fẹ mọ'lé bàbá alájọ mí (bàbá alájọ mí)
Ọ'tá fẹ mọ ìgi lẹ'yìn ogba mí
Wọn fẹ mọ'ye t'ówà ní ipamọ mí oh
Bàbá mí lókè ńpá mí mọ
Wọn rò pé ó tàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Àdúrà lo ń gbà àgbàrá ko (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
Oṣó ń gb'ogun, ọ'tá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
(2T on the mix)

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar